Nengi Omuku
Ìrísí
Nengi Omuku | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Nengi Omuku Born 1987 Delta State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Slade School of Fine Art, University College London |
Iṣẹ́ | Artist, photographer |
Gbajúmọ̀ fún | Artist, sculpture |
Awards | British Council CHOGM art award |
Website | nengiomuku.com |
Nengi Omuku (tí wọ́n bí ní ọdún 1987) jẹ́ ayàwòrán, agbẹ́gilére àti oníṣẹ́-ọnà ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria.[1][2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí i ní ìlú Asaba, Ìpínlẹ̀ Delta ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Omuku kẹ́kọ̀ọ́ gboyè B.A. àti M.A, ní Slade School of Fine Art, University College London.[4][5][6]
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- I can't feel my legs, March 2012, oil on canvas, 220 x 160 cm.
- Botticelli, April 2012, oil on canvas, 100 x 140 cm.
- Corkscrew October 2014.[7]
- Room with a view, 2020, oil on sanyan 130 x 190 cm[8]
- What was lost, 2020, oil on sanyan 208 x 243 cm[9]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣé Nengi Omuku ti mu kí ó gba ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ àti àmì-ẹ̀yẹ lọ́pọ̀lọpọ̀ títí kan àmì-ẹ̀yẹ British Council CHOGM, láti ọwọ́ Queen Elizabeth II kejì [10][11][12]
- 2012 Prankerd Jones Memorial Prize Awarded by University College London
- 2011 Nancy Balfour MA Scholarship Awarded by University College London
- 2003 Winner- British Council CHOGM art competition Awarded by Queen Elisabeth II
Àwọn ìṣàfihàn rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdáṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Kristin Hjellegjerde Gallery, Berlin (2021)
- Gathering, Kristin Hjellegjerde Gallery, London (2020)
- Stages of Collapse, September Gray, Atlanta (2017)
- A State of Mind, The Armory Show, New York (2016)
- A State of Mind, Omenka Gallery, Lagos (2015)
- To Figure an Encounter, Open The Gate, London (2011).
Àjọṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- La Galerie, Contemporary art Center, Noisy-le-Sec (2021)
- All the Days and Nights, Kristin Hjellegjerde Gallery, London (2020)
- Untitled Art San Francisco, with Kristin Hjellegjerde Gallery, San Francisco (2020)
- 1-54 Contemporary African Art Fair, London (2019), Hospital Rooms, Griffin Gallery, London (2018)
- At work, Arthouse, Lagos (2018); ARTX,Lagos (2017)
- Commotion, 1:54, London (2017); Mapping Histories, Constructing Realities, ART15, London (2015)
- The Next 50 Years, Omenka Gallery, Lagos (2014)
- Jerwood Drawing Prize Exhibition, Jerwood Gallery, London (2012).
- Deep Cuts Last Measures, Stephen Lawrence Gallery, London (2011)
- Surplus to Requirements, Slade Research Center, London (2011)
- The Future of Contemporary Art, Lloyd Gill Gallery, Bristol (2010)
- Group Exhibition, Swiss Cottage Gallery, London (2010)
- Group Exhibition, Camden Art Gallery, London (2009)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nengi Omuku". Creatives Database (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-05-01. Archived from the original on 2021-08-09. Retrieved 2021-08-09.
- ↑ Onuzo, Chibundu (17 June 2021). "'If you are of the camp that wants to keep the art world an exclusive club, then look away now'" (in en-US). The Art Newspaper. Archived from the original on 2021-08-09. https://web.archive.org/web/20210809124755/https://www.theartnewspaper.com/comment/opening-up-to-new-audiences.
- ↑ "Artwork exhibition in London captures trauma of Nigerian youths". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-08. Retrieved 2021-08-09.
- ↑ Uzoho, Victor Ifeanyi (24 January 2018). "Six artists for Arthouse' s At Work 2018 exhibition". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). The Guardian Nigeria. Archived from the original on 2018-01-30. Retrieved 2018-02-17.
- ↑ "Nengi Omuku – Biography". SMO Contemporary Art (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-09.
- ↑ Mitter, Siddhartha (2019-02-08). "Lagos, City of Hustle, Builds an Art 'Ecosystem'" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2019/02/08/arts/design/lagos-nigeria-art-x-art.html.
- ↑ "NENGI OMUKU". Contemporary And (in Èdè Jámánì). Retrieved 2021-08-09.
- ↑ Walton, Millie (2020-12-04). "Painting the Collective: An Interview with Nengi Omuku". Trebuchet (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-09.
- ↑ "Nengi Omuku – Works". Kristin Hjellegjerde (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-09.
- ↑ "Nengi Omuku – Overview". Kristin Hjellegjerde (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-09.
- ↑ "Nengi Omuku – September Gray" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-09.
- ↑ "Nengi Omuku". www.artskop.com. Archived from the original on 2021-08-09. Retrieved 2021-08-09.