Jump to content

Nosa Omoregie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:DMCÀdàkọ:Merge partner

Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the Nigerian recording artiste. Fún other uses, ẹ wo: Nosa Omoregie.
Nosa Omoregie
Orúkọ àbísọNosa Omoregie
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kejì 1981 (1981-02-26) (ọmọ ọdún 43)
Edo State, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Benin City, Edo State, Nigeria
Irú orinCCM, Contemporary worship music, Gospel
Occupation(s)Singer-songwriter, performer, worship leader, musician, producer
InstrumentsVocals, Piano,Guitar
Years active(2009–present)
LabelsChocolate City, Salt Music
Associated actsNathaniel Bassey, MI, Ice Prince, Zee, Masterkraft, Frank Edwards, Dammy Krane, Sasha P, Seyi Shay, Milli
Websitesaltmusic.ng

Nosa Omoregie, tí a mọ̀ mọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i Nosa, jẹ́ oníṣẹ́-ọnàNàìjíríà, olórin, a-kọ-orin àti eléré. Ó wà lábẹ́ Warner Music Group African partner lọ́wọ́lọ́wọ́, Chocolate City.[1][2]

  1. Animashaun, Ayo (27 October 2013). "The Difference between Church and Gospel Music – Nosa". Hip Hop World Magazine. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 2014-08-22. 
  2. Nwamu, Aniebo (30 March 2014). "'Marriage Not on My Mind Yet' – Nosa | Nigerian News from Leadership Newspapers". Leadership.ng. Retrieved 2014-08-22. 

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nosa Omoregie, tí wọ́n mọ̀ ní ṣókí gẹ́gẹ́ bí i Nosa, ni wọ́n bí ní 26 oṣù kejì ọdún 1981, ó jẹ́ ọmọ ìlú Benin City, Ìpínlẹ̀ Edo.

Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ní Yunifásítì Benin (UNIBEN). Ìpínlẹ̀ Edo [1]

  1. "What I want in my woman – Nosa Omoregie". Punchng.com. 6 July 2014. Archived from the original on 22 August 2014. Retrieved 2014-08-22. 

Orísun ayọ̀ Nosa gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí ó ń dàgbà wà nínú orin àti lílọ sí ilé ìjọsìn, níbi tí ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àmúlò àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ tí ń gbèrú. Ó bẹ̀rẹ̀ nínú ẹgbẹ́ akọrin ọmọdé ní ilé ìjọsìn, àwọn olórin ẹ̀mí bí i Fred Hammond àti Kim Burrell sì ni wọ́n jẹ́ ẹṣin iwájú tí ó ń wò sáré àti àwọn ẹgbẹ́ olórin R n B Boyz II men. Ó ní láti nífẹ̀ẹ́ orin jazz àti orin soul àti lẹ́yìn náà orin rock nígbà tí ó yá, fún rírọrùn tí ó rọrùn. Ó tún jẹ́ aṣàwòkọ́ṣe ńlá Afro-Highlife[1] pàápàá orin láti ọwọ́ Sonny Okosun, Christy Essien-Igbokwe, King Sunny Adé àti Onyeka Onwenu, fún ìdí èyí ó mú láti inú ọ̀pọ̀ èròǹgbà ọmọdé fún iṣẹ́ láti di onímọ̀ ẹ̀rọ, jagunjagun, agbábọ́ọ̀lù sí dídi aṣàgbéjáde orin àti olórin.[2]

Èròǹgbà Nosa pẹ̀lú iṣẹ́ orin rẹ̀ ni láti dí àlàfo irúfẹ́ orin nígbà tí ó ń rí i dájú pé abala orin ẹ̀mí rẹ̀ wà ní ipele iwájú pátápátá gẹ́gẹ́ bí àwọn irúfẹ́ orin mìíràn èyí ni pé irúfẹ́ àpapọ̀ tí ó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀: tí ó ń ṣe àtinúdá orin ẹ̀mí lórí ìlù high-life , ẹsẹ high-life pẹ̀lú ègbè tí ó jọ mọ́ rock-y tàbí kíkọ orin 'àdàmọ̀dì' Òyìnbó pẹ̀lú àdídùn R n B nígbà tí ó bá ń ṣe ìwàásù iṣẹ́ amóríwú tàbí amọ́kànyá sí àwọn olùgbọ́ rẹ̀. .[1]

Wọ́n ṣe àgbéjáde àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́, Open Doors, ní 14 oṣù kẹta 2014 ó sì ṣe àtìlẹ́yìn rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹyọ orin "Always Pray for You", "Why You Love Me" àti "Always on My Mind".[3] Àti bákan náà ní oṣù karùn-ún 2014, ó pawọ́pọ̀ pẹ̀lú Nokia fún àgbéjáde orin rẹ̀ "Love is Calling".[4] Ní ọjọ́ 16 oṣù karùn-ún 2014, ìwé ìròyìn The Punch sọ pé Nosa tọwọ́bọ̀wé àdéhùn iṣẹ́ ìpolówó pẹ̀lú Unilever.[5] Ní ọjọ́ 26, oṣù kejì 2020, tí ó tún jẹ́ ọjọ́ ìbí rẹ̀, Nosa bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀ Salt Music.[6]

Iṣẹ́ orin àti orin-ẹyọ tí ó gbé e jáde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nosa lọ sí abẹ́ ilé-iṣẹ́ orin Chocolate City ní 2012.[7] Ní 11 oṣù kọkànlá 2009 Nosa ṣe àgbéjáde orin-ẹyọ rẹ̀ àkọ́kọ́, "Always Pray for You", lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Chocolate City. "Always Pray for You" jẹ́ ẹyọ-orin Nosa àkọ́kọ́ .[8]

  1. 1.0 1.1 "What I want in my woman – Nosa Omoregie". Punchng.com. 6 July 2014. Archived from the original on 22 August 2014. Retrieved 2014-08-22. 
  2. "Becoming a soldier was my biggest dream as a child –Nosa Omoregie". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-23. 
  3. "Chocolate City's NOSA Drops Debut Album". P.M. NEWS Nigeria. 14 March 2014. Retrieved 2014-08-22. 
  4. "Nokia Endorses NOSA". P.M. NEWS Nigeria. 28 May 2014. Retrieved 2014-08-22. 
  5. "Nosa grabs licensing deal with Close-Up". Punchng.com. 16 May 2014. Archived from the original on 5 July 2014. Retrieved 2014-08-22. 
  6. Nicegospel (2020-02-29). "Nosa Floats Record Label – Salt Music » Nicegospel". Nice Gospel  » Download Latest Gospel Songs 2019 / 2020 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 5 October 2022. Retrieved 2020-03-13. 
  7. "Chocolate City records signs nosa". Hip Hop World Magazine. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 20 August 2014. 
  8. "Nosa – Always Pray For You". notjustok.com. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 20 August 2014. 

Àtòjọ orin rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́-ọnà tí ó ṣáájú
Ọdún Àkọ́lé Àwo
2009 / 2013 "Always Pray for You" Open Doors
2013 "Why You Love Me"
2014 "Always on My Mind"
2016 "I am Blessed"[2]
2016 "God Is Good"[3]
2017 "Most High" (feat. Nathaniel bassey)[4]
2018 "We Will Arise" (feat. LCGC)[5]
2019 Na Your Way Ft. Mairo Ese [6]
2020 "Dry Bones"
Àwọn ẹyọ-orin tí kò sí nínú iṣẹ́ rẹ̀
2014 "Always on My Mind (Remix)"

(Nosa featuring MI)

Non Album Singles
Gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́-ọnà tí wọ́n pè sí orin
2011 "Standing"

(Zee featuring Nosa)

Non-album single
2013 "New Day"

(Masterkraft featuring Frank Edwards, Nosa)

2014 "Fly Like The Eagles"

(Ice Prince featuring Dammy Krane, Sasha P, Seyi Shay)

  1. "Nosa walks into the door Jeremiah Gyang once opened [Album Review] | Nigerian Entertainment Today – Nigeria's Number 1 Entertainment Daily". Thenet.ng. Archived from the original on 31 August 2014. Retrieved 2014-08-22.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Gerardcole (2016-10-02). "Music: Nosa - Blessed". NetNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-14. 
  3. "Nosa - 'God is good'". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-09-29. Retrieved 2019-06-14. 
  4. "'Most high' ft Nathaniel Bassey". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-07-03. Retrieved 2019-06-14. 
  5. "MUSIC: Nosa – We Will Arise". 360Nobs.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-14. Archived from the original on 24 September 2020. Retrieved 2019-06-14. 
  6. "Listen To Nosa's Genuine Description Of God In "Na Your Way"". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-30. Archived from the original on 19 June 2022. Retrieved 2019-10-03.