Odò Límpopó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Odò Límpopó
River
Limpopo River in Mozambique
Àwọn orílẹ̀-èdè South Africa, Botswana, Zimbabwe, Mozambique
Mouth Indian Ocean
Length 1,750 km (1,087 mi)
Basin 415,000 km² (160,232 sq mi)
Discharge
 - average 170 m3/s (6,003 cu ft/s)

Odò Límpopó gbera ni aringbongan apaguusu Afrika, o si unsan lo si owo ilaorun de inu Okun India. O gun to bi 1,750 kilometres (1,087 mi), pelu itobi adogun omi 415,000 square kilometres (160,200 sq mi).



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Coordinates: 25°10′S 33°35′E / 25.167°S 33.583°E / -25.167; 33.583