Ogun abẹ́lé
Ogun abẹ́lé ni ogun tó bá ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ẹgbẹ́ ológun ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ méjì tí wọ́n jẹ́ ará orílẹ̀-èdè kan náà[1], tàbí, nígbà míràn, láàrin àwọn orílẹ̀-èdè méjì tí wọ́n jẹ́ dídá láti orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ kan[2]. Ohun tí ẹ̀gbẹ́ kan únfẹ́ le jẹ́ láti gba ìjọba orílẹ̀-èdè tàbí agbègbè kan, láti gba òmìnira agbègbè kan tàbí ṣe ìyípadà ètò ìjọba[1]. Ogun abẹ́lé, civil war lédè gẹ̀ẹ́sì, jẹ́ àmúwá láti èdè Látìnì civile bellum níbi tí wọ́n ti kọ́kọ́ lòó láti ṣeìjúwe orísirísi ọ̀pọ̀ ogun abẹ́lé tó ṣẹlẹ̀ ní Ilẹ̀ Rómù ní ọ̀rúndún 1k s.K.
Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ 1.0 1.1 James Fearon, "Iraq's Civil War" Archived 2007-03-17 at the Wayback Machine. in Foreign Affairs, March/April 2007. For further discussion on civil war classification, see the section "Formal classification".
- ↑ Nations, Markets, and War: Modern History and the American Civil War | Book Reviews, EH.net. "Two nations [within the U.S.] developed because of slavery." October 2006. Retrieved July 2009.