Ojú Kòkòrò
Ojú kòkòrò: Greed | |
---|---|
Adarí | Dare Olaitan |
Olùgbékalẹ̀ | Olufemi D. Ogunsanwo Dare Olaitan |
Àwọn òṣèré | Wale Ojo Tope Tedela Charles Etubiebi Seun Ajayi Ali Nuhu Shawn Faqua Somkele Iyamah Emmanuel Ikubese |
Ìyàwòrán sinimá | Baba Agba |
Olóòtú | Seun Opabisi |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Singularity Media House Gabriel Studios BCI Studios |
Olùpín | FilmOne Distributions |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 110 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English Yoruba Bini |
Ojú Kòkòrò: Greed, jẹ́ eré sinimá agbéléwò tí ó jẹ́ àkójọ àwọn eré crime-heist comedy film tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2016, tí àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bíi : Wale Ojo, Tope Tedela, Charles Etubiebi, Seun Ajayi, Shawn Faqua, Ali Nuhu, Somkele Iyamah, Emmanuel Ikubese àti Afeez Oyetoro ti kópa. Dáre Ọláìtán ni ó darí eré yí nígbà tí Olufemi D. Ogunsanwo jẹ́ olùgbéré náà jáde. [1]
Olaitan ni ó ke eré yí ní ọdún 2014, eré yí ni ó jẹ́ akọ́kọ́ eré tí yóò kọ́kọ́ kọ parí tí yóò si di gbígbé jáde Wọ́n ṣe ṣe agbékalẹ̀ eré náà ní ìlànà tí ó fi bá àkókò kọ̀ọ̀kan mu tí ó sì mú àwọn òṣèré ati ònwòran lọ́kàn. Wọ́n gbé eré náà jáde ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù Kẹta ọdún 2014. Olaitan wrote Ojukokoro in 2014.[2][3][4]
Agbékalẹ̀ eré náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n fi eré Ojú kòkòrò sọ ìtàn òṣìṣẹ́ adarí ilé-iṣẹ́ epo kan tí ó gbèrò láti digun ja àwọn ọ̀gá rẹ̀ lólè, amọ́ tí ó padà ronú pìwàdà nígbà tí ó ronú wípé èrò òun kò dára [5]
Àwọn òṣèré olùkópa inú rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Tope Tedela gẹ́gẹ́ bí Sunday
- Charles Etubiebi gẹ́gẹ́ bí Manager
- Wale Ojo gẹ́gẹ́ bí Mad Dog Max
- Seun Ajayi gẹ́gẹ́ bí Monday
- Ali Nuhu gẹ́gẹ́ bí Jubril
- Shawn Faqua gẹ́gẹ́ bí Rambo
- Somkele Iyamah gẹ́gẹ́ bí Sade
- Afeez Oyetoro gẹ́gẹ́ bí (Saka)
- Emmanuel Ikubese gẹ́gẹ́ bí The Accountant
- Sammie Eddie gẹ́gẹ́ bí DJ
- Gbolahan Olatunde
- Kayode Olaiya (Aderupoko)
- Linda Ejiofor
- Kunle Remi
- Zainab Balogunfil
Bí wọ́n ṣe gbé eré náà jáde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń ya àwòrán eré náà ní inú oṣù Kẹrin ọdún 2016. Wọ́n kọ́kọ́ gbé ìfáàrà eré náà jáde ní inú oṣù Kẹrin ọdún 2016. Principal Photography began in April 2016. [6] Ní inú osù Kínní ọdún 2017, wọ́n gbé eré náà jáde ní pẹrẹu.[7]
Ìpele bí wọ́n ṣe gbée jáde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n ṣàfihàn eré náà ní sinimá ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún osù Kẹta ọdún 2017 ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n tún ṣàfihàn rẹ̀ ní sinimá ilẹ̀ New York láàrín ọjọ́ kẹtàlá sí ọjọ́ọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù Kẹrin ọdún 2018. Bákan náà ni ìkanì Netflix náà ṣàfihàn rẹ̀ ní ìlú USA ní inú oṣù kẹrin ọdún 2021.[8]
Àwọn itọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ojukokoro (Greed) Is In Cinemas This Friday, See Photos & Comments From Premiere". lindaikejisblog.com. Retrieved 23 October 2017.
- ↑ "Film Review: In Dare Olaitan’s Ojukokoro, greed is good » YNaija". ynaija.com. 18 March 2017. Retrieved 23 October 2017.
- ↑ Staff, Konbini (20 March 2017). "'Ojukokoro (Greed)' Is Proof All Nollywood Needs Is A Good Script". konbini.com. Archived from the original on 23 October 2017. Retrieved 23 October 2017.
- ↑ Izuzu, Chidumga. "Pulse Movie Review: Mixed with violence and humour; "Ojukokoro" is uniquely entertaining". pulse.ng. Archived from the original on 13 March 2017. Retrieved 23 October 2017.
- ↑ Izuzu, Chidumga. "Nolly Thursdays: Tope Tedela, Seun Ajayi, Beverly Naya attend "Ojukokoro" premiere". pulse.ng. Archived from the original on 15 June 2017. Retrieved 23 October 2017.
- ↑ Izuzu, Chidumga. ""Ojukokoro (Greed)": Watch Tope Tedela, Linda Ejiofor, Somkele Idahalama in trailer". pulse.ng. Archived from the original on 25 May 2017. Retrieved 23 October 2017.
- ↑ Dare Olaitan (27 January 2017). "OJUKOKORO (GREED) TRAILER MARCH 17TH!". Retrieved 23 October 2017 – via YouTube.
- ↑ Oke, Tolu (8 April 2021). "Ojukokoro Set To Make Netflix Debut On Friday". The Culture Custodian (Est. 2014). Retrieved 25 April 2021.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ojukokoro (Greed) , (IMDb) (Gẹ̀ẹ́sì)
- Official Instagram