Jump to content

Òkè Olúmọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Oke Olumo)

Òkè Olúmọ ni òkè kan tí nó wà ní ilẹ̀ Ẹ̀gbá ìlú Abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Òkè Olúmọ jẹ́ ibìsálà fún àwọn ará Abẹ́òkúta ní àsìkò ogun abẹ́lé ní àsìkò 19th century. Wọ́n sì ń bọ òkè náà gẹ́gẹ́ bí Òrìṣà tí wọ́n sì ń bọọ́ pẹ̀lú oríṣríṣi ẹbọ.[1]

Àbẹ̀wò sí òkè Olúmọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òkè Olúmọ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn òkè gbajúmọ̀ tí àwọn ènìyàn ma ń lọ bẹ̀wò láti gbafẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3]

Òkè Olúmọ

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]