Jump to content

Olaide Adewale Akinremi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olaide Adewale Akinremi
Member of the House of Representative from Oyo State
In office
11 June 2019 – 10 July 2024
ConstituencyIbadan North
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1972-10-01)1 Oṣù Kẹ̀wá 1972
Aláìsí10 July 2024(2024-07-10) (ọmọ ọdún 51)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress (APC)

Olaide Adewale Akinremi (1 October 1972 – 10 July 2024) je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà láti ẹgbẹ́ All Progressives Congress . O je ọmọ ilé ìgbìmò aṣòfin to n sosójú Ibadan North lati odọdún 19 titi o fi ku lolódun 24.[1]

Akinremi to ṣoju ẹgbẹ oṣelu APC lo jawe olubori nínú eto ìbò ọdún 2019 lati ṣojú ẹkun ìdìbò Àríwá Ibadan, o bori PDP Ademola Omotoso ati awọn oludije ẹgbẹ mejila miiran. Akinremi gba 33.88% ibo, nígbàtí ti Omotoso gba 32.26%. [2] wọn tun yàn gẹgẹbi oludije ni ọdun fun 2023 idibo ó sì jawe olubori.

Akinremi ku lójijì ni ọjọ kẹwàá oṣù Keje ọdún 2024, ni ẹni ọdun 51.[3] [4]