Jump to content

Omotosho Olakunle Rasaq

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Omotosho Olakunle Rasaq
Member of the Kwara State House of Assembly
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
18 March 2023
Member of the Kwara State House of Assembly
from Isin Local Government
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
18 March 2023
ConstituencyOke-onigbin
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí3 Oṣù Kàrún 1973 (1973-05-03) (ọmọ ọdún 51)
Agbonda,Irepodun Local Government Kwara State Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
Alma mater
Occupation
  • Politician
  • Accountant

Omotosho Olakunle Rasaq jẹ́ olóṣèlú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó ń ṣàmójútó agbègbè Isin, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Isin, ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ilẹ̀ Kwara.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Rasaq ní ọjọ́ karùn-ún oṣù Kẹta ọdún 1973 ní Oke-Onigbin, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Isin, ní Ìpínlẹ̀ Kwara, Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé-ìwé Oke-Onigbin Community primary school àti Oke-Onigbin Secondary School láàárín ọdún 1986-1995. Ó gba oyè National Diploma (Nigeria) àti ìwẹ́-ẹ̀rí Higher National Diploma láti Kwara State Polytechnic ní ọdún 1998 àti 2003 bákan náà.

Rasaq jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ètò Ìṣirò owó àti Olùdásílè Àgbà ti ilé-iṣẹ́ Bellumin Int’l àti Oko Omo Aro kí ó tó wọ iṣẹ́ Òṣèlú, nígbà tí ó díje dupò kan lábẹ́ àsíà Accord Party ní ọdún 2007 kí ó tó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ olóṣèlú All Progressive Congress láti díje dupò ní ọdún 2023 tí ó sì wọlé gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan lára àwọn Ọmọ-ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ aṣòfin ẹlẹ́ẹ̀kẹwàá ti ìpínlẹ̀ Kwara.

  1. "HON. OMOTOSHO OLAKUNLE RASAQ". Kwara State House of Assembly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-12-03.