Oníṣe:Agbalagba/Lánre Towry-Coker
Dr. Lanre Towry-Coker FRIBA ni wọ́n bí ní ọdún (1944) , tí ó sì jẹ oníṣẹ́ ayàwòrán ilé, olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà,[1] . Ó ti ṣiṣẹ́ lábẹ́ ìjọba àti aládàáni rí, tí ó sì jẹ́ Kọmíṣánà àkọ́kọ́ fún iṣẹ́ àti ilégbèé ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[2][3][4] nígbà kan rí.
Igbesi-aye ati iṣẹ-ibẹrẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó dá ilé iṣé ayàwòrán rẹ̀ kalẹ̀ tí ó pé ní He established his architectural firm, (Towry-Coker Associates), ní ọdún 1975,[5] in 1976. Gẹ́gébí ó ṣe jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Èkó i wọòn ṣe fi orúkọ àdúgbò kan sọrí rẹ̀ nílùú Èkó, ìyẹn ní Lagos Island tí wọ́n ń pè ní (Towty Street) láti gi bu ọlà fún àwọn ẹbí rẹ̀. Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n fètò sí orílẹ̀ olú ìlú [4]Àbújá, tí ó sì ti gba àmì ẹ̀yẹ lọ́pọ̀lọpọ̀ fún àwọn iṣẹ́ mánigbàgbé pàá pàá jùlọ, àwọn ilé àrá-m-barà tí ó ti pètò rẹ nílẹ̀ Nàìjíríà.[4]
NÍ ọdún1999, Towry-Coker ni ẹni àkọ́kọ tó kọ́kọ́ jẹ́ Kọmíṣánà fún iṣe àti ilégbèé ní ìpínlẹ̀ Èkó. Òun ni ònkọ̀wé [2] [3] [4] Housing Policy àti The Dynamics Of Housing Delivery Ni Nigeria: tí ó sì lo ìpínlẹ̀ Èkó gẹ́gẹ́ bí ìwòye, tí ilé iṣẹ́ MakeWay tẹ̀ jáde ní ọdún 2012. [6]
Towry-Coker jẹ́ Olùkọ́ni ti Institute of Architects (NFIA) àti alábàáṣepọ̀ ti Institute Institute of Arbitrators (ACI. Arb.) ní ìlú UK. [4] Ní ọdún 2017, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí olùdásílẹ̀ Royal Institute of British Architects , ní ilẹ̀ Nàìjíríà àti ọkan nínú àwọn ayàwòrán ọgbọ̀n ní gbogbo àgbáyé ni Naijiria ati ọkan ninu awọn oluṣaworan ọgbọn ní gbogbo àgbáyé. [7]
Ó fẹ́ ìyàwó rẹ̀ Bísífẹ Towry-Coker ṣùgbọ́n wọ́n ti pín yà báyìí. [2] [8] Ó bí àwọn ọmọ obìnrin mẹ́ta pẹ̀lú ọkùn rin kan Ọláòtán. [3]
Ẹ tún lé wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- HAkojọ awọn oniseworan ile Naijiria
- ↑ "‘Nigeria Needs New Housing Policy’". Leadership News. 3 May 2014. http://leadership.ng/business/369315/nigeria-needs-new-housing-policy. Retrieved 18 March 2015.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 "Lagos socialite, Lanre Towry-Coker's lonely world". 15 January 2015. http://www.thecapital.ng/index.php/home/1538-lagos-socialite-lanre-towry-coker-s-lonely-world. Retrieved 18 March 2015.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 Empty citation (help)
- ↑ 4.0 4.1 4.2 4.3 4.4 Kemi Akinyemi, "Celebrating Society Patriarch, Lanre Towry-Coker at 70", The Elites Nigeria, 15 November 2014. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "Elites" defined multiple times with different content - ↑ Yinka Kolawole (11 July 2011). "FMBN has failed to deliver on housing finance – Towry-Coker". The Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2011/07/fmbn-has-failed-to-deliver-on-housing-finance-towry-coker/. Retrieved 18 March 2015.
- ↑ Housing Policy and the Dynamics of Housing Delivery in Nigeria: Lagos State as Case Study, MakeWay Publications, 2012, ISBN 978-1907925177.
- ↑ "Awọn ọmọ ẹgbẹ RIBA 2017" , Architecture.com, 2017.
- ↑ "For the Towry-Cokers, it’s a cold war". New Telegraph. 19 April 2014. http://newtelegraphonline.com/towry-cokers-cold-war/. Retrieved 18 March 2015.
- "Aṣayan Imọlẹ: Oluworan Lanre Towry-Coker (Ph.D.)" , Naijiria Aja , 1 Okudu 2015.
- Kemi Akinyemi, "Ayẹyẹ Awujọ Patriarch, Lanre Towry-Coker ni 70" , Awọn Elites Nigeria , 15 Kọkànlá Oṣù 2014.
[[Ẹ̀ka:Àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà]] [[Ẹ̀ka:Àwọn ènìyàn alààyè]] [[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1944]] [[Ẹ̀ka:Pages with unreviewed translations]]