Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia
Jump to navigation
Jump to search
|
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia (Socialist Federal Republic of Yugoslavia; SFRY) je orile-ede Yugoslafia to wa lati igba Ogun Agbaye Keji (1943) titi di igba to je tituka deede ni 1992 larin awon Ogun Yugoslafia. O je orile-ede sosialisti ati ile apapo to ni awon orile-ede olominira mefa: Bosnia ati Herzegovina, Kroatia, Macedonia, Montenegro, Serbia, ati Slovenia. Serbia, bakanna, tun ni igberiko aladawa meji ti Vojvodina ati Kosovo.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |