Orun mooru
Orun Mooru | |
---|---|
Adarí | Ola Balogun |
Olùgbékalẹ̀ | Moses Olaiya |
Òǹkọ̀wé | Ola Balogun |
Àwọn òṣèré | Moses Olaiya |
Ìyàwòrán sinimá | Tunde Kelani |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Alawada Movies ltd. |
Déètì àgbéjáde | 1982 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Ìnáwó | ₦1,500,000 |
Orun Mooru (Heaven is Hot) jẹ́ eré apanilẹ́rìn-ín tí a gbé jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1982. Adarí eré náà ni Ola Balogun eré náà jẹ́ gbígbé jáde láti ọwọ́ Moses Olaiya (Baba Sala). Eré náà sọ ìtàn nípa ọkùnrin olókoòwò tí ó ti fi ìgbà kan lówó rí, ẹni tí ó bọ́ sí ọwọ́ babaláwo èké kan nípa ṣíṣe ògùn àti tètè lówó èyí tí kò bọ́ síi get-rich-quick scheme, lẹ́yìn èyí ni ó wá gbèrò àti gbẹ̀mí ara rẹ̀.[1]
Ìhun ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orun Mooru sọ nípa ìtàn Karounwi (Moses Olaiya), ẹni tí ó jẹ ahun-apẹ̀rẹ̀ (basketmaker) tí ó ń gbé ní ìlú tí wọ́n tíń pa ẹja. Ìsàpèpadà ìrírí jẹ́ kí á mọ̀ pé ó ti fi ìgbà kan lògbà rí gẹ́gẹ́ bíi oníṣòwò, kí ó tó bọ́ sọ́wọ́ babaláwo èké nípa níní èrò pé òun le di olówó tabua.
Karounwi gba owó-ìyá tótó ₦500 láti ọwọ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀. Ó pàdánù gbogbo owó; ìdajì sí ọwọ́ olè alọ́nilọ́wọ́gbà, èyí tí ó ṣẹ́kù tí ó kó pamọ́ sínú ìlú ni ìyàwó rẹ̀ gbé lọ láti fi pàrọ̀ abọ́. Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ó sún un láti gbẹ̀mí ara rẹ̀ tí ó sì ti ibẹ̀ di ẹni ilẹ̀pa tí ó sì bá ara rẹ̀ ní ìlú àwọn oku.
Iku (means: Death) Ikú sọ fún un pé òun kò retí rẹ̀ torí àsìkò rẹ̀ kò rí ì tó, ni Karounwi bá lọ Ayọ̀ (means: Joy), ẹni tí ó dá appadàsí ilé ayé pẹ̀lú ẹyin agbára méjì àti méjì nínú àwọn ọmọ lẹ́yìn rẹ̀.
Nígbà tí ó dé inú ayé ni ó bá ara rẹ̀ nínú ilé ńlá kan, Karounwi bá àwọn ọmọ ẹ̀yìn Ayo méjèèjì lòpọ̀, lẹ́yìn èyí ni ó fọ́ ẹyin kan nínú méjì tí Ayo fún un èyí tí ó yí padà di owó jaburata. Lẹ́yìn èyí ni ó kọ etí ikún sí ìmọ̀ràn tí wọ́n fún un láti tẹ̀lé, ó fọ́ ẹyin kejì èyí tí ó yí padà tí ó di ikú.
Àwọn òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Moses Olaiya as Lamidi
- King Sunny Ade as himself (cameo)
- Ola Balogun
Gbígbé jáde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n ya ojúlówó eré náà sí 35 mm film, ṣùgbọ́n tí wọ́n dín in kù sí 16 mm film fún gbígbé ká àti ṣíṣe lafihàn.[2]
Wọ́n ya ayé kejì eré náà ní Osun Grove, Osogbo.[1]
Àríwísí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orun Mooru jẹ́ eré tó àṣeyọrí, kí wọ́n tó gé àṣeyọrí rẹ̀ kúrú nípa ṣíṣe ẹ̀dà rẹ̀, kí ó tó padà wọ orí ìtàgé. [1]
Critical reception
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kenneth W. Harrow states: "The themes of over-reaching greed and wild swings from the village life from the lavish property and back again, are close to the heart Nigerian national experience during the oil boom years [...] Propelled by his moral wills, Baba Sala bounces among four sharply opposing realms".[1]
Piracy
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Not long after the theatrical release of Orun Mooru, it got pirated and bootlegged following the theft of the film's master celluloid tape.[1][2] The piracy happened before the end of the theatrical run of the film; several cinemas in different cities across the country screened the film without being licensed to do so and remuneration never reached the producers.[3] The loss incurred as a result of this piracy significantly affected the career of Moses Olaiya in the film industry, as well as his personal life.[4][5][2][6][7] The piracy of Orun Mooru has been reported as a first major incidence of piracy in the Nigerian film industry.[2][8][9]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 Harrow, Kenneth W. (1999) (in en). African Cinema: Postcolonial and Feminist Readings. Africa World Press. ISBN 9780865436978. https://books.google.com/books?id=kRR2fBv2NhUC&q=orun%2520mooru&pg=PA160.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 "I Was The First Actor To Be Dealt With By Pirates -Baba Sala". www.nigeriafilms.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-24.
- ↑ Makinde, Femi. "Baba Sala forgave those who pirated Orun Mooru before he died –Emmanuel, son". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-24.
- ↑ (in en) Glendora Review. Glendora International (Nigeria) Limited. 2001. https://books.google.com/books?id=NsQwAQAAIAAJ&q=orun+mooru.
- ↑ Bada, Gbenga. "7 movies produced by Baba Sala and which he played lead roles" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-25. Retrieved 2018-11-24.
- ↑ Adeyemo, Adeolu (2017-05-27). "Bala Sala: I never recovered from my Orun Mooru travails". www.newtelegraphng.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-25. Retrieved 2018-11-24.
- ↑ "Things you didn't know about Moses Olaiya aka ( Baba Sala ) – INFORMATION NIGERIA". INFORMATION NIGERIA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-14. Retrieved 2018-11-24.
- ↑ Odejimi, Segun (2018-10-08). "Moses Olaiya Adejumo (Baba Sala): The Comedy Legend Who Was Brutally Attacked By Pirates". TNS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-25. Retrieved 2018-11-25.
- ↑ Adejumo-Ayibiowu, Oyindamola (2018-11-14). "Nigeria: Beyond Laughter, a Purvey of Baba Sala's Role in Nigeria's Economic Development". The Guardian (Lagos). Retrieved 2018-11-25.