Jump to content

Ossie Davis

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ossie Davis
photo by Carl Van Vechten, 1951
Ọjọ́ìbíRaiford Chatman Davis
Iṣẹ́Actor, director, poet, playwright, writer, activist
Ìgbà iṣẹ́1939–2005
Olólùfẹ́Ruby Dee (1948-2005; his death)

Ossie Davis (December 18, 1917 – February 4, 2005) je omo Afrika-Amerika osere filmu, oludari filmu, akoewi, olukoere, olukowe, ati alakitiyan awujo.

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Davis je bibi bi Raiford Chatman Davis ni Cogdell, Clinch County, Georgia, omokunrin Kince Charles Davis, onise-ero iko oko ojuirin, ati iyawo re Laura Cooper.[1] The name Ossie came from a county clerk who misheard his mother's pronunciation of his initials "R.C." when he was born.[2] Bi awon obi re se fe, o lo gbeko ni Yunifasiti Howard sugbon o kuro nibe laipari ni 1939 lati ba bere sini se ise osere ni ilu New York; lojowaju o lo gbeko ni Ile-Eko Gbogbo Imo Yunifasitu Kolumbia. Ise osere re, to gba ewadun meje, bere ni 1939 pelu Rose McClendon Players ni Harlem. O se filmu akoko re ni 1950 ninu filmu Sidney Poitier No Way Out. Ohun ni ohun Anansi alantakun lori ere telifisan awon omode Sesame Street lori PBS niti aworan alamurin re.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ossie Davis Biography". filmreference. 2008. Retrieved 2009-01-22. 
  2. "Ossie Davis Biography". Internet Movie Database. 2008. Retrieved 2007-01-11.