Oyekan I
Oba Oyekan I | |
---|---|
Ọba ìlú Èkó
| |
Oba of Lagos
| |
Reign | 1885 - 1900 |
Coronation | 1885 |
Predecessor | Dosunmu |
Successor | Eshugbayi Eleko |
House | Akitoye, Dosunmu |
Father | Oba Dosunmu |
Born | 1871 Lagos, Nigeria |
Died | September 30, 1900 Lagos |
Burial | Iga Idunganran |
Oba Oyekan I (ó kú ní ọjọ́ ogbọ̀n oṣù Kẹ̀sán ọdún 1900) joba gẹ́gẹ́ bí Ọba ìlú Èkó láti oṣù kẹta ọdún 1885 sí ọjọ́ ogbọ̀n oṣù Kẹ̀sán ọdún 1900. Ó gun orí ìtẹ́ lẹ́yìn oṣù kan tí bàbá rẹ̀ Oba Dosunmu kú.[1]
Ọmọ ọba Oyekan vs Olóyè Apena Ajasa ìṣẹ̀lẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní 1883, Oba Dosunmu, bàbá Oyekan pe ìpàdé láti wo wàhálà láàrin Olóyè Apena Ajasa àti Olóyè Taiwo Olowo síbẹ̀síbẹ̀ Olóyè Ajasa ń halẹ̀ sí Ọba àti àwọn ìjòyè tó kù. Nígbà tí o ń wo ipò tí Apena Ajasa fí ń halẹ̀, ọmọ ọba Oyekan gbá Olóyè Ajasa ní etí tí ó sì sọ pé Ajasa ko yẹ kí o bú Ọba ni Iga Idunganran (ààfin Ọba). Ọba Dosunmu ko gba ìwà Oyekan, ó si bù lépè pé" Ọmọkùnrin tó ti hùwà báyìí kí o sọnù" . Olóyè Taiwo Olowo, orogún Olóyè Apena Ajasa inú re dun nípa ìgbésí Oyekan, o sì kojú ète sí Oba Dosunmu wí pé" Ọmọkùnrin náà kò ní ṣófo ṣùgbọ́n ẹ̀mí rẹ yóò gùn" [2]
Idinku ni ipa ti Obaship nigba ijọba Oyekan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ikú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọba Oyekan kú ní ọjọ́ ìṣẹ́jú, oṣù kẹsàn-án ọdún 1900 lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣe àìsàn fún ìgbà díẹ̀. Ó jọba fún ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (15) gẹ́gẹ́ bí Ọba ti Èkó. [3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Folami, Takiu (1982). A History of Lagos, Nigeria: The Shaping of an African City. Exposition Press, 1982. pp. 37–40. ISBN 9780682497725.
- ↑ Losi, John. History of Lagos. African Education Press (1967). p. 52.
- ↑ Folami, Takiu. A History of Lagos, Nigeria: The Shaping of an African City. Exposition Press, 1982. ISBN 9780682497725.