Jump to content

Pablo César

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pablo César
Ọjọ́ìbíPablo César
26 Oṣù Kejì 1962 (1962-02-26) (ọmọ ọdún 62)
Buenos Aires, Argentina
Orílẹ̀-èdèArgentine
Iléẹ̀kọ́ gígaFundación Universidad del Cine
Iṣẹ́Director, producer, writer, actor, editor
Ìgbà iṣẹ́1977–present

Pablo César (tí wọ́n bí ní 26 Oṣù Kínní, Ọdún 1962), jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Argẹntínà.[1][2] Ó ti lọ́wọ́sí sinimá ilẹ̀ Áfríkà pẹ̀lú dídarí àwọn eré bíi Equinox, the Garden of the Roses, Los dioses de agua àti Aphrodite, the Garden of the Perfumes.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Pablo Cesar: Buenos Aires, Argentina". otroscines. Retrieved 27 October 2020. 
  2. "FILMS DIRECTED BY Pablo César". letterboxd. Retrieved 27 October 2020. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Africa for beginners". otroscines. Archived from the original on 23 November 2021. Retrieved 27 October 2020.