Jump to content

Paul Igwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Paul Igwe
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kọkànlá 1977 (1977-11-27) (ọmọ ọdún 47)
Ìpínlẹ̀ Èkó,
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Olùgbéré-jáde
Ìgbà iṣẹ́1998–present
Websitewhitestonetv.com/

Paul Igwe Wọ́n bí Paul Igwe ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kọkànlá ọdún 1977. Òun ni olùdásílẹ̀ "Whitestine Cinema". Ó jẹ́ olùgbéré-jáde, ònkọ̀wé, àti ẹni tí ó gba amì-ẹ̀yẹ fún dídarí ètò orí ẹrọ amóhù-máwòrán, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ó ni eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkólé rẹ̀ ń jẹ́ Clinic Matters, The Bemjamins, Ojays àti Asunder" tí ó sì darí àwọn eré náà.[1]

Ní ọdún 2000, Ó bérẹ̀ ilé-iṣẹ́ ìgbéré-jáde rẹ̀ tí ó pè ní Whitestone Cinema tí ó ti darí àti gbé eré tí ó tó ogún jáde pẹ̀lú àwọn eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ tí ó tó mẹ́jọ jáde. Igwe di gbajú-gbajà ní ọdún 2000 lẹ̀yìn tí ó kópa nínú eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Outrageous", ati ipa lààmì-laaka tí ó kó nínú eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Extended Family" tí ó jẹ́ eré onípele mọ́kàndílógójì ní ọdún 2007. [2] Ó dá ilé-iṣẹ́ sinimá tirẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 2009, ó sì kọ eré ọlósòọ̀sẹ̀ tirẹ̀ Clinic Matters tí ó ń gbé jáde láti ilé-iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2009. Eré yí ti gba amì-ẹ̀yẹ oríṣiríṣi lábẹ́lé àti lókè ọ̀kun tí ó fi mọ́ àmì-ẹ̀yẹ 'World Quality Commitment Award ní orílẹ̀-èdè Paris ní ọdún 2018.[3][4][5]

Ní inú oṣù Kejì ọdún 2012, ó gbé eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ rẹ̀ kejì tí ó pè ní The Benjamins, eré tí wọ́n yàn fún amì-ẹ̀yẹ 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards fún eré onípele tí ó dára jùlọ.[6][7][8]

Ó bẹ̀rẹ̀ eré onípele míràn tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Ojays ní ọdún 2015 tí wọ́n yan eré náà fún amì-ẹ̀yẹ Nafca Awards fún eré onípele apani-lẹ́rín jùlọ.[9] Paul tún gbọ̀nà àrà yọ pẹ̀lú bí ó ṣe gbé àkànṣe ètò kan kalẹ̀ tí ó pè ní "USEKWU IGBO", tí ó túmọ̀ sí Iyàrá ìdáná Ìgbò. Ètò yí náà ti àmì-ẹ̀yẹ ti 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards fún ètò orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán tí peregedé jùlọ ní ọdún 2016, èyí tó wáyé ní gbọ̀ngàn Èkó HotelÌpínlẹ̀ Èkó. [10][11][12][13][14] Paul tún gbé eré ọlósọ̀ọ̀sẹ̀ onípele mìíràn jáde ní ọdún 2016 tí ó pe àkọ̀lé rẹ̀ ní House 6. [15] tí "Troubled Cottage" sì tún tẹ̀legsa.[16] Ó tún gbé eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ míràn tí ó pè ní Asunder tí ó ń ṣafihàn ẹbí àti ìgbéyàwó ẹbí kọ̀kan jáde ní ìparí ọdún 2019 yí kan náà. [17][18][19][20][21][22]

Ó gbé eré onípele mìíràn jáde ní èdè Ìgbò tí ó pe akọ́lé eré náà ní "Nkewa" ní ọdún 2017, tí wọ́n fi han ní orí Africa Magic Igbo.[23] Òun náà ló darí eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́"Dance To My Beat", eré tí Joseph Benjamin, Kehinde Bankole, Tóyìn Abraham, àti Mary Remmy Njoku ti kópa.[24][25][26][27]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Eré
2000 Outrageous
2007 Extended Family
2009 Clinic Matters
2012 The Benjamins
2015 OJAYS
2015 PULSE
2015 USEKWU IGBO
2016 House 6
2016 Ulo Isii
2016 Troubled Cottage
2016 Asunder
2017 Nkewa
2017 Dance To My Beat

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "EMCOAN plans CEO training and end of year gig – The Nation Nigeria" (in en-US). The Nation Nigeria. 8 November 2017. http://thenationonlineng.net/emcoan-plans-ceo-training-end-year-gig/. 
  2. Michael, John (21 May 2017). "5 Nigerian TV Shows From the Past That Deserve A Remake" (in en-GB). vibe.ng. http://www.vibe.ng/5-nigerian-tv-shows-past-deserve-remake/. 
  3. "Clinic Matters: What’s gwan?" (in en-gb). Modern Ghana. https://www.modernghana.com/movie/13624/clinic-matters-whats-gwan.html. 
  4. Editor (30 October 2012). "MUST READ!: Producer Of Popular Sitcom, "Clinic Matters" Honoured In Paris". MUST READ!. Retrieved 12 September 2018. 
  5. "Nigerians Share: Top 10 TV Shows in 2013 • Connect Nigeria". connectnigeria.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 12 September 2018. Retrieved 12 September 2018. 
  6. "Movie awards: All the winners of the AMVCA – PM NEWS Nigeria" (in en-US). PM NEWS Nigeria. 9 March 2014. https://www.pmnewsnigeria.com/2014/03/09/movie-awards-all-the-winners-of-the-amvca/. 
  7. "Nairobi Half-life, The Contract, Flower Girl win big at Africa Magic Viewers’ Choice Awards – Premium Times Nigeria" (in en-GB). Premium Times Nigeria. 10 March 2014. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/156457-nairobi-half-life-contract-flower-girl-win-big-africa-magic-viewers-choice-awards.html. 
  8. Ejiofor, Clement (9 March 2014). "Funke Akindele, Rita Dominic, Yvonne Okoro Win Big At 2014 AMVCA" (in en-US). Naija.ng – Nigeria news.. https://www.naija.ng/61313.html#40596. 
  9. Izuzu, Chidumga. "NAFCA 2015: "Black November," "30 Days in Atlanta," "Oloibiri" lead nominees list" (in en-US). Archived from the original on 12 September 2018. https://web.archive.org/web/20180912204258/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/nafca-2015-black-november-30-days-in-atlanta-oloibiri-lead-nominees-list-id3932115.html. 
  10. "Check out the full list of winners at 2016 AMVCA". Linda Ikeji's Blog (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 September 2018. 
  11. Izuzu, Chidumga. "AMVCA 2016: "Dry," Adesua Etomi, Daniel K Daniel win big [full list of winners"] (in en-US). Archived from the original on 12 September 2018. https://web.archive.org/web/20180912204424/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/amvca-2016-dry-adesua-etomi-daniel-k-daniel-win-big-full-list-of-winners-id4751815.html. 
  12. Igwe, H. (6 March 2016). "Check out the full list of winners at the AMVCA 2016" (in en-US). Naija.ng – Nigeria news.. https://www.naija.ng/754209-check-full-list-winners-amvca-2016.html#754209. 
  13. "AMVCA 2016: Full winners list". Africa Magic Official Website – AMVCA 2016: Full winners list (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 September 2018. 
  14. "AMVCA 2016 : See list of winners – Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 5 March 2016. https://www.vanguardngr.com/2016/03/617370/. 
  15. "Africa Magic IGBO". Africa Magic Official Website – Africa Magic IGBO (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 September 2018. 
  16. "Kwesé". www.kwese.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 12 September 2018. Retrieved 12 September 2018. 
  17. "African Movie Channel set to launch Asunder" (in en-US). Archived from the original on 12 September 2018. https://web.archive.org/web/20180912204616/https://guardian.ng/art/african-movie-channel-set-to-launch-asunder/. 
  18. "Benita Nzeribe, Lilian Esoro, Nonso Odogwu, Maureen Okpoko, Tessy Oragwa attend the Official Launch of African Movie Channel's First TV Series – Asunder – BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 September 2018. 
  19. "Benita Nzeribe, Lilian Esoro, Teju Babyface Attend the Official Launch of Asunder TV Series – INFORMATION NIGERIA" (in en-US). INFORMATION NIGERIA. 16 December 2016. http://www.informationng.com/2016/12/benita-nzeribe-lilian-esoro-teju-babyface-attend-official-launch-asunder-tv-series.html. 
  20. "Asunder TV series premieres in Lagos – Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 29 December 2016. https://www.vanguardngr.com/2016/12/asunder-tv-series-premieres-lagos/. 
  21. Izuzu, Chidumga. ""Asunder": New TV series to premiere in January" (in en-US). Archived from the original on 12 September 2018. https://web.archive.org/web/20180912204323/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/asunder-new-tv-series-to-premiere-in-january-id5831522.html. 
  22. "Official Launch of African Movie Channel’s First TV Series – Asunder | African Movie Channel". www.africanmoviechannel.tv (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 12 September 2018. Retrieved 12 September 2018. 
  23. "Africa Magic IGBO". Africa Magic Official Website – Africa Magic IGBO (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 September 2018. 
  24. Bamidele, Bose, Joseph Benjamin, Kehinde Bankole, Mary Njoku, Toyin Abraham & more, star in Mary Lazarus’ Movie Debut as a Producer "Dance To My Beat"  – Goldmyne.TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), archived from the original on 12 September 2018, retrieved 12 September 2018 
  25. "Dance To My Beat | Nollywood REinvented" (in en-US). Nollywood REinvented. 31 July 2018. https://www.nollywoodreinvented.com/2018/07/dance-to-my-beat.html. 
  26. Izuzu, Chidumga. ""Dance to My Beat": See cast of movie in Christmas photo shoot" (in en-US). Archived from the original on 12 September 2018. https://web.archive.org/web/20180912204554/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/dance-to-my-beat-see-cast-of-movie-in-christmas-photo-shoot-id5927506.html. 
  27. "Film Review: Dance To My Beat is a shameless cash grab. But you will laugh » YNaija". ynaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 September 2018. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control