Midé Fúnmi Martins: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
k * -words/*
Ìlà 1: Ìlà 1:
'''Midé Fúnmi Martins''' (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1979) jẹ́ Òṣeré-bìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ [[Yoruba|Yorùbá]] lórílẹ̀-èdè [[Naijiria|Nàìjíríà]]. Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé [[Fúnmi Martin's]] tó ṣaláìsí lọ́dún 2002. Midé Martins darapọ̀ mọ́ àwọn Òṣeré sinimá àgbéléwò ní kété tí ìyá rẹ di olóògbé. Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ sí [[Afeez Owó]].<ref name="Punch Newspapers 2015">{{cite web|title=Friends gave my wife wrong advice to ruin our marriage –Afeez Owo|website=Punch Newspapers|date=2015-12-15|url=https://punchng.com/friends-gave-my-wife-wrong-advice-to-ruin-our-marriage-afeez-owo/|access-date=2019-10-05}}</ref> Ọmọ méjì ni ó bí .<ref name="Informationcradle 2017">{{cite web|title=Mide Martins Bio, Age, Father, Husband Age, Instagram, Movies And More|website=Informationcradle|date=2017-07-25|url=https://informationcradle.com/africa/mide-martins/|access-date=2019-10-05}}</ref>
'''Midé Fúnmi Martins''' (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1979) jẹ́ Òṣeré-bìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ [[Yoruba|Yorùbá]] lórílẹ̀-èdè [[Naijiria|Nàìjíríà]]. Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé [[Fúnmi Martins]] tó ṣaláìsí lọ́dún 2002. Midé Martins darapọ̀ mọ́ àwọn Òṣeré sinimá àgbéléwò ní kété tí ìyá rẹ di olóògbé. Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ sí [[Afeez Owó]].<ref name="Punch Newspapers 2015">{{cite web|title=Friends gave my wife wrong advice to ruin our marriage –Afeez Owo|website=Punch Newspapers|date=2015-12-15|url=https://punchng.com/friends-gave-my-wife-wrong-advice-to-ruin-our-marriage-afeez-owo/|access-date=2019-10-05}}</ref> Ọmọ méjì ni ó bí .<ref name="Informationcradle 2017">{{cite web|title=Mide Martins Bio, Age, Father, Husband Age, Instagram, Movies And More|website=Informationcradle|date=2017-07-25|url=https://informationcradle.com/africa/mide-martins/|access-date=2019-10-05}}</ref>


==Àwọn Ìtọ́kasí==
==Àwọn Ìtọ́kasí==

Àtúnyẹ̀wò ní 21:19, 23 Oṣù Kẹ̀wá 2020

Midé Fúnmi Martins (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1979) jẹ́ Òṣeré-bìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé Fúnmi Martins tó ṣaláìsí lọ́dún 2002. Midé Martins darapọ̀ mọ́ àwọn Òṣeré sinimá àgbéléwò ní kété tí ìyá rẹ di olóògbé. Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ sí Afeez Owó.[1] Ọmọ méjì ni ó bí .[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Friends gave my wife wrong advice to ruin our marriage –Afeez Owo". Punch Newspapers. 2015-12-15. Retrieved 2019-10-05. 
  2. "Mide Martins Bio, Age, Father, Husband Age, Instagram, Movies And More". Informationcradle. 2017-07-25. Retrieved 2019-10-05.