Jump to content

Rẹ̀mí Àlùkò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

'Adérẹ̀mí Àlùkò tí gbogno ènìyàn tún mọ̀ sí Igwe, Bàbá Àràbà , Àjélà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ jẹ́ olórin ọ̀kọrin Fújì àti òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1]

Wọ́n bí Rẹ̀mí Àlùkò ní ìlú Èbúté Mẹ́taÌpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1977. Àmọ́, àwọn bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú IléṣàÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Abẹ́òkútaÌpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ẹ̀wé, Rẹ̀mí ma ń tẹnu mọ wípé ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó ni òun ń ṣe. Olórin Fújì yí jẹ́ ẹlẹ́sìn ọmọ lẹ́yìn Kírísítì, bí ó tilẹ̀.jẹ́ wípé wọ́n ma ń fọn rere rẹ̀ wípé àwọn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí ni wọ́n lorin fújì.

Awuye-wuye nípa ojú rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lásìkò ìgbà kan, ìròyìn gbe awuye-wuye tí ó ń jà ràn-ìn nípa Alùkò wípé óbti pàdánù ojú rẹ̀. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Remi Aluko Biography - Net Worth, Age, Songs & Album". FujiNaija. 2020-04-13. Retrieved 2020-11-29. 
  2. "Fuji music act, Remi Aluko unveils real story of his rumoured blindness". Encomium Magazine. 2020-11-29. Retrieved 2020-11-29.