Jump to content

Remembrance Arcade (Lagos)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Remembrance Arcade o wa ni Tafawa Balewa Square, ìpinlè Eko, jẹ aaye ti o wa fun sisé iranti awọn ọmọ-ogun Naijiria ti o ku ni Ogun Agbaye akọkọ, Ogun Agbaye Keji ati Ogun Abele Naijiria . O wa laarin Tafawa Balewa Square ni Eko Central Business District. A ma un se awọn ayẹyẹ Iranti Awọn ologun ni ọdọọdun ni aaye yii.[1][2] Ni ẹnu-ọna aaye naa, ere ọmọ-ogun kan ti orúko rè o jé mimo wà pẹlu ibon ni enu ònà ti ó sì ún nkọju si ẹnu-ọna.

  1. "Pictorial: Sanwo-Olu lays wreath on Armed Forces Remembrance Day". Punch Newspapers. January 15, 2022. Retrieved September 12, 2022. 
  2. "Remembrance Day: Sanwo-Olu commends security officers on peace keeping". Vanguard News. January 15, 2021. Retrieved September 12, 2022.