Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà
Biafra independent state map-en.svg
Orileijoba alominira Orile-ede Olominira ile Biafra ni Osu Kefa 1967.
Ìgbà July 6, 1967–January 15, 1970
Ibùdó Nigeria
Àbọ̀ Nigerian victory
Àwọn agbógun tira wọn
 Nigeria
 Egypt (air force only)[1]

Supported by:[1][2]
 United Kingdom
 Soviet Union
 Syria
 Sudan
 Chad
 Niger
 Saudi Arabia

Àdàkọ:Country data Biafra

Mercenaries
Supported by:[3][4][4][5]
 Israel
 South Africa
Àdàkọ:Country data Rhodesia
 France
 Portugal

Àwọn apàṣẹ
Nàìjíríà Yakubu Gowon
Nàìjíríà Murtala Mohammed
Nàìjíríà Benjamin Adekunle
Nàìjíríà Olusegun Obasanjo
Àdàkọ:Country data Biafra Odumegwu Ojukwu
Àdàkọ:Country data Biafra Philip Effiong
Òfò àti ìfarapa
200,000 Military and civilian casualties 1,000,000 Military and civilian casualties

Ogún Abẹ́lé Nàìjíríà wáyé láàárín ọjọ́ Kẹfà Oṣù Okúdù Ọdún 1967 sí ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́: tí a tún mọ̀ sí (Ogun Nàìjíríà - Biafra tàbí Ogun Biafra) jẹ́ Ogun Abẹ́lé tí ó wáyé láàárín ìjọba Nàìjíríà àti orílè-èdè Biafra, Ìpínlẹ̀ tí ó fé dádúró tì ó ti fẹ́ gba òmìnira kúrò lára Nàìjíríà ní ọdún 1967. Ọgágun Yakubu Gowon ni ó ń darí Orílẹ̀èdè Nàìjíríà Lt. Colonel Odumegwu Ojukwu sí ń darí Biafra. Èròngbà àwọn olùfẹ́ ẹ̀yà Ìgbò tí wọ́n rò pé àwọn kò lè bá ìjọba àpapọ̀ ṣe mọ torí pé àwọn Mùsùlùmí ẹ̀yà  Haúsá-Fúlàní tí àríwá Orílẹ̀èdè tí jẹ gàba ní Biafra. Ìyọrísí ìkọlù yìí láti rògbòdìyàn  ìṣèlú, ọrọ̀ ajé, ẹ̀yà, ajẹmáṣà àti ẹ̀sìn ló bí pínpín Nàìjíríà láti ọdún 1960  sí 1963. Lára àwọn aṣokùnfà ogun ní ọdún 1966 ni ìjà ẹ̀sìn àti ìṣègbè ẹ̀yà Ìgbò ní Apá Àríwá Nàìjíríà. Ìdìtẹ̀gbàjọba, àti ìrẹ́jẹ àwọn Ìgbò ní apá àríwá Naijiria. Bákan náà Ìjẹgàba lórí ìgbéjáde epo rọ̀bì tó lére gọbọi lórí ní Niger Delta náà kópa ribiribi.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]