Reuben Muoka
Ìrísí
Reuben Muoka jẹ́ olóòtú ìbánisọ̀rọ̀ fún Vanguard Newspaper nígbà kan rí, ó sì tún fìgbà kan jẹ́ olùdarí àgbà fún Nigeria First Mobile Telephone Operator, lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jẹ́ olùdarí public affairs fún Nigerian Communications Commission.[1][2]
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Muoka kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ iṣẹ́ tíátà ní University of Ilorin. Ó sì tún lọ sí University of Lagos láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Mass Communications, níbi tí ó ti fara ṣíṣẹ́ nínú Public Relations àti Advertising.[3][4]
Ẹgbẹ́ tó dara pọ̀ mọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Muoka jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́; Nigerian Union of Journalist, Nigeria Institute of Public Relations àti Registered Practitioners of Advertising.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Reuben Muoka appointed NCC's director public affairs - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-23. Retrieved 2022-06-25.
- ↑ "NCC appoints Reuben Muoka as Director Public Affairs - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2022-06-25.
- ↑ Ezugwu, Obinna. "Reuben Muoka Replaces Ikechukwu Adinde As NCC's Director Of Public Affairs - Business Hallmark". hallmarknews.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-25.
- ↑ "NCC appoints Reuben Muoka as Director Public Affairs - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2022-06-25.
- ↑ "Reuben Muoka appointed NCC's director public affairs - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-23. Retrieved 2022-06-25.