Richard Bamisile
Ìrísí
Richard Bamisile | |
---|---|
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Richard Olufemi Bamisile 27 Oṣù Kẹ̀sán 1965 Ibadan, Western State, Nigeria (now in Oyo State, Nigeria) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
Alma mater | Government College, Lagos University of Ado-Ekiti (now Ekiti State University) |
Occupation | Politician, businessman |
Website | teambafem.com |
Nickname(s) | BAFEM |
Richard Olufemi Bamisile (ẹni tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí BAFEM; wọ́n bí i ní 27 September 1965) jẹ́ Olóṣèlú Nàìjíríà tí ó sì jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tó ń ṣojú Agbègbè Gúúsù Èkìtì II.[1] Ó tún jẹ́ Agbẹnusọ ilé aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkìtì nígbà kan rí (ìjókòó kẹta).[2] Ó wà lára àwọn olùdíje fún ipò Gómìnà nínú ètò ìdìbò abẹ́nú ẹgbẹ́ òṣèlú (APC) ní 2019.[3][4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ekiti 2022: House of Reps member, Bamisile, joins guber race". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-10. Retrieved 2022-03-18.
- ↑ "Ekiti 2022: House of Reps member, Bamisile, joins guber race". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-10. Retrieved 2022-02-21.
- ↑ "ekiti-2018 nobody can rig apc primary". Daily POst. March 30, 2018.
- ↑ "Appeal court nullifies election in ekiti". osundefender.com. Archived from the original on 2018-08-29. Retrieved 2023-12-07.
- ↑ "ekiti guber elections olufemi bamisile becomes picks up apc nomination form". niajaparrot.com. Archived from the original on 2018-06-20. Retrieved 2023-12-07.