Jump to content

Richard E. Taylor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Richard Edward Taylor
Ìbí2 Oṣù Kọkànlá 1929 (1929-11-02) (ọmọ ọdún 94)
Medicine Hat, Alberta
PápáParticle physics
Ilé-ẹ̀kọ́SLAC
LBL
École Normale Supérieure
Ibi ẹ̀kọ́Stanford
University of Alberta
Doctoral advisorRobert F. Mozley
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1990)

Richard Edward Taylor, CC, FRS, FRSC (ojoibi November 2, 1929 ni Medicine Hat, Alberta) je ojogbon omo Kanada-Amerika ni Yunifasitu Stanford.[1] Ni 1990, o pin Ebun Nobel ninu Fisiksi pelu Jerome Friedman ati Henry Kendall "fun iwadi asiwaju won nipa fifankiri awon elektroni lori protoni ati neutroni, to se pataki fun idagbasoke afijuwe quark ninu fisiksi atasere."[2]