Subrahmanyan Chandrasekhar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Subrahmanyan Chandrasekhar
Subrahmanyan Chandrasekhar
Ìbí(1910-10-19)Oṣù Kẹ̀wá 19, 1910
Lahore, Punjab, British India
AláìsíAugust 21, 1995(1995-08-21) (ọmọ ọdún 84)
Chicago, Illinois, United States
Ọmọ orílẹ̀-èdèBritish India (1910–1947)
India (1947–1953)
United States (1953–1995)
PápáAstrophysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Chicago
University of Cambridge
Ibi ẹ̀kọ́Trinity College, Cambridge
Presidency College, Madras
Doctoral advisorR.H. Fowler
Doctoral studentsDonald Edward Osterbrock, Roland Winston
Ó gbajúmọ̀ fúnChandrasekhar limit
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize, Physics (1983)
Copley Medal (1984)
National Medal of Science (1966)
Padma Vibhushan (1968)
Religious stanceHindu atheist[1]

Subrahmanyan Chandrasekhar, FRS (Tàmil: சுப்பிரமணியன் சந்திரசேகர்), English: /ˌtʃʌndrəˈʃeɪkɑr/)[2] (October 19, 1910 – August 21, 1995)[3] je onimo fisiksi-irawo omo India Amerika. O je elebun Nobel ninu fisiksi pelu William Alfred Fowler fun ise won lori opo elero ati iyojade awon irawo.[4] O je abatan Elebun Nobel omo India Sir C. V. Raman.

Chandrasekhar sise ni eka-eko ni Yunifasiti ilu Chicago lati 1937 titi di igba to ku ni 1995 nigba to je omo odun 84. O di araalu orile-ede Amerika ni 1953.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Chandrasekhar: The Man Behind the Legend - Chandra Remembered. By Kameshwar C. Wali - 1997; London: Imperial College Press. ISBN 1-86094-038-2
  2. Àdàkọ:Indian name
  3. Bio-Chandrasekhar
  4. Vishveshwara, S. (25 April 2000). "Leaves from an unwritten diary: S. Chandrasekhar, Reminiscences and Reflections" (.PDF). Current Science 78 (8): 1025–1033. http://www.ias.ac.in/currsci/apr252000/generalia.pdf. Retrieved 2008-02-27.