Jump to content

Saint Obi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Obinna Nwafor
Fáìlì:Saint-Obi resize.jpg
Ọjọ́ìbí(1965-11-16)16 Oṣù Kọkànlá 1965
Aláìsí7 May 2023(2023-05-07) (ọmọ ọdún 57)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Jos
Ìgbà iṣẹ́1996—2023
Gbajúmọ̀ fúnÀdàkọ:Bulleted list

Obinna Nwafor 9 (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún Oṣù Kọkànlá ọdún 1965, tí ó sì kú ní ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 2023) tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Saint Obi, jẹ́ òṣèré ọmọ Nàìjíríà,[1][2] olóòtú fíímù àti olùdarí fíìmù.[3][4][5] Òbí ni a mọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínú fíímù Candle Light, State of Emergency, Sakobi, Goodbye Tomorrow, Heart of Gold, Festival of Fire, Executive Crime and Last Party.

Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ ẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Obi ní ọjọ́ kẹrìndínlógún Oṣù Kọkànlá ọdún1965.[6] Ó ṣe pàtó ìmọ̀ Iṣẹ tiata èyiun Theatre Arts ni University of Jos,[7] ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré-oníṣe ní ọdún 1996 nípasẹ̀ tẹlifisiọnu Peugeot.[8] Ní ọdún 2001, Obi ṣe fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Take Me to Maama, níbití ó ti kópa bí Jerry, papọ̀ pẹ̀lú Ebi Sam, Rachel Oniga, Nse Abel ati Enebeli Elebuwa.

Obi kú ní Oṣù Karùn-ún ọjọ́ keje, ọdún 2023, ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta.[9]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Adebayo, Tireni (24 February 2022). "Actor Saint Obi battles wife in court over custody of their kids". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 March 2022. 
  2. Ukonu, Ivory; THEWILL (25 February 2022). "Veteran Actor Saint Obi In Messy Divorce Drama With Estranged Wife" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 23 November 2022. 
  3. "Saint Obi’s night of double treats". punchng.com. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 21 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Saint Obi out with new awards". punchng.com. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 21 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Nollywood Actor Saint Obi Reveals why he stopped acting!". 2shymusic.com. Archived from the original on 9 August 2020. Retrieved 21 August 2014. 
  6. NF. "Saint Obi: Biography, Career, Movies & More" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 19 May 2019. 
  7. "Life and Times of Saint Obi". Vanguard News. 2023-05-14. Retrieved 2023-06-02. 
  8. "Over 500 million watch Nollywood, says Saint Obi". Vanguard. 15 August 2009. http://www.vanguardngr.com/2009/08/over-500-million-watch-nollywood-says-saint-obi/. Retrieved 23 April 2011. 
  9. Veteran Nolywood actor, Saint Obi dies at 57