Sam Amuka-Pemu
Ìrísí
Sam Amuka Pemu (tí a bí ní oṣù kẹfà, ojo ketala ọdún 1935) je oniroyin ni orile Ede Nàìjíríà, òǹkọ̀wé ati òǹtẹ̀wéjádé aṣáájú nínú àwọn ìwé ìròyìn tí a mọ sì ìwé ìròyìn Vanguard àti ti gbajumo ìwé ìròyìn Punch.[1][2] Ó jé ọmọ bibi ìlú Sapele ni igobo to ìpínlè Delta ni apa àríwá ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà gba owó olóògbé pá amuka àti Ayaba Teshoma Amuka-Pemu tí ó kú ní oṣù karùn-ún ọdún 2014.[3][4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Agency reporter (12 June 2015). "Buhari pays tribute to Amuka-Pemu at 80". The Nation. Retrieved 16 June 2015.
- ↑ "Robbery Attack: I Was Shaken — Vanguard Publisher, Sam Amuka-Pemu", PM News, 18 August 2011.
- ↑ "Sam Amuka Loses Mum". ThisDay Live. Archived from the original on 15 June 2015. Retrieved 16 June 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Jonathan Mourns Gombe Emir *Kutigi's wife, Amuka-Pemu's mom too". Metro Watch. 28 May 2014. Retrieved 16 June 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Uduaghan consoles ‘Sad Sam’ over mother’s death". Vanguard News. Retrieved 16 June 2015.