Saul Zaentz
Saul Zaentz | |
---|---|
Zaentz ní àmì ẹyẹ Academy kejìdínládọ́ta ní ọdún 1976 | |
Ọjọ́ìbí | Passaic, New Jersey, United States | Oṣù Kejì 28, 1921
Aláìsí | January 3, 2014 San Francisco, California, United States | (ọmọ ọdún 92)
Orílẹ̀-èdè | American |
Ẹ̀kọ́ | Rutgers University |
Iṣẹ́ |
|
Saul Zaentz ( /ˈzænts/; Ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kejì ọdún 1921 – ọjọ́ kẹta oṣù kejì ọdún 2014) jẹ́ ọmọ olùṣe fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó gba àmì ẹyẹ Academy Award for Best Picture ní emeta, ní 1996, ó sì gba àmì ẹyẹ Irving G. Thalberg Memorial Award.
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Zaentz ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1921, ní Passaic, New Jersey, òun ni àbíkẹ́yìn nínú ọmọ márùn-ún.[1][2][3] Àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ àwọn ará Júù tí ó wá láti Poland.[1]
Gẹ́gẹ́ bi ọmọdé, Zaentz lọ ilé ìwé William B. Cruz Memorial number 11 ní Passaic. Lẹ́yìn ìgbà tí ó jà gẹ́gẹ́ ọmọ ológun Orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà ní Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì, Zaentz bẹ̀rẹ̀ sí ń nífẹ̀ẹ́ sí orin ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Jazz at the Philharmonic àti Norman Granz. Ó kàwé ní Rutgers lẹ́yìn ogun GI Bill.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Saul Zaentz, film and music mogul, 1921–2014". Financial Times. January 10, 2014. Archived from the original on December 10, 2022. Retrieved 2021-09-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ International Television & Video Almanac. Quigley Publishing Company. 2006. ISBN 9780900610783. https://books.google.com/books?id=kSQYAAAAIAAJ&q=%22zaentz,+saul%22+1921+february. Retrieved November 22, 2015.
- ↑ R.I.P. Saul Zaentz, Deadline.com; retrieved January 4, 2014.
- ↑ Robert D. McFaddenjan (2014-01-04). "Saul Zaentz, Producer of Oscar-Winning Movies, Dies at 92". The New York Times. Retrieved 2016-03-28.