Segun Awosanya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Advert Àdàkọ:Use Nigerian English

Segalink
Ọjọ́ìbíAdesegun Olusegun Omotayo Awosanya
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Lagos
Iṣẹ́Realtor, Human Rights Activist, Business & Strategic Consultant
Gbajúmọ̀ fúnFounder/President, Social Intervention Advocacy Foundation (SIAF)
Olólùfẹ́Odezi Faith Awosanya
Websitesegalink.com/

Segun Awosanya, tí ìnagijẹ rẹ ń jẹ́ Segalink,[1] jẹ́ ọmọ orílé-èdè Nàìjíríà.[2] ajìjà gbara, ajà fún ẹ̀tọ́ ọmọniyan, oníṣòwò àti olùfọ̀rọ̀lọ̀.


Awosanya jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àwọn ìgbìmò tí ó bu ẹnu àtẹ̀ lu ìwà jẹgúdú-jẹrá tí àwọn Ọlọ́pàá ń wù. Tí ó sì lo ìtàkùn ẹ̀rọ ayélujára láti fi èyí sí àwọn tí ó di ipò àṣẹ ìjọba mú. àn. #EndSARS #ReformPoli. -èyí ni ó mú kí ìjọba Buhari fagilé ìgbìmò àjọ tí ó ń gbé ogún ti ìwà ọ̀daràn àti lílu Íjíbítì lórí ìtàkùn àgbáyé as SARS.[3][4][5]<ref>{{cite news |last1=Channels Television News

Career[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awosanya [6][7].[8].[9][10] ni olùsílẹ̀ àti Ààrẹ ẹgbẹ́ (SIAF). Òun tún ni olùdásílẹ̀ àti olùdarí ALIENSMEDIA (ẹgbẹ́ tí ó ń rí sí ènìyàn, ìmọ̀-ìjìnlẹ̀, àti ète) Ó tẹ̀síwájú láti máa gba àwọn ènìyàn níyànjú lórí ẹ̀rọ abẹ́yẹ́fò Twitter, léyìí tí ó fún àwọn ènìyàn ní àǹfààní láti mọ ẹ̀tọ́, mọ̀fin.

Awosanya[11] tí bèrè fún iranlọwọ lọ́wọ́ ìjọba àti àjọ tí kò rọgboku léjọba ní Nàìjíríà. Pàápàá jù lọ lórí eto okowo, ọ̀rọ̀ ajé, ìrònilágbára, àti sisamulo ẹ̀rọ ayalejura

|title=SARS Overhaul: Operatives To Wear Uniform, Restricted To Robbery, Kidnap Cases |url=https://www.channelstv.com/2018/08/24/sars-reform-operatives-to-wear-uniform-restricted-to-robbery-kidnap-cases/ |accessdate=9 September 2018

  1. "EndSARS: Why I supported reopening of Lekki tollgate -Segalink". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-02-07. Retrieved 2021-04-13. 
  2. Zaza Hlalethwa,"#ENDSARS: Understanding Nigeria's anti police brutality protests". news24.com. 12 October 2020. https://www.news24.com/arts/culture/endsars-understanding-nigerias-anti-police-brutality-protests-20201012. Retrieved 15 January 2020. 
  3. The Guardian. "Nigerian Presidency Has Received The #EndSars Petition- Segun Awosanya". https://guardian.ng/life/nigerian-presidency-has-received-the-endsars-petition-segun-awosanya/. Retrieved 9 September 2018. 
  4. CNN. "How a social media movement against police brutality prompted Nigerian government to act". https://edition.cnn.com/2018/08/20/africa/nigeria-police-brutality-report/index.html. Retrieved 9 September 2018. 
  5. Premiumtimes. "#EndSARS: Nigerians applaud Osinbajo over directive to review SARS". premiumtimesng.com. https://www.premiumtimesng.com/news/top-news/280141-endsars-nigerians-applaud-osinbajo-over-directive-to-review-sars.html. Retrieved 9 September 2018. 
  6. Valentine Iwenwanne,"Protesters in Nigeria Demand a Proper End to Police Unit That Tortures Detainees". vice.com. 12 October 2020. https://www.vice.com/en/article/4ayk4d/sars-police-unit-nigeria-dissolve-torture. Retrieved 15 January 2020. 
  7. "Commissioners of police, DPOs couldn't control IRT, STS operatives — CSOs". vanguardngr.com. 18 July 2020. https://www.vanguardngr.com/2020/07/commissioners-of-police-dpos-couldnt-control-irt-sts-operatives-csos/. Retrieved 15 January 2020. 
  8. Adaobi Onyeakaegbu,"Segun "Segalink" Awosanya is our Man Crush today!". pulse.ng. 17 December 2018. https://www.pulse.ng/lifestyle/food-travel/segun-segalink-awosanya-is-our-man-crush-today/lhzr604. Retrieved 15 January 2020. 
  9. Sampson Toromade,"The #EndSARS Protester is Pulse Person of the Year 2020". pulse.ng. 30 December 2020. https://www.pulse.ng/news/local/pulse-person-of-the-year-endsars-protester/fbkevcq. Retrieved 15 January 2020. 
  10. Titilola Oludimu,"Social Media Round: Overhaul SARS". techpoint.africa. 17 August 2018. https://techpoint.africa/2018/08/17/overhaul-sars/. Retrieved 15 January 2020. 
  11. "#EndSARS: Almost A Revolution". thisdaylive.com. 13 October 2020. https://www.thisdaylive.com/index.php/2020/10/13/endsars-almost-a-revolution/. Retrieved 15 January 2020.