Jump to content

Àgùtàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Sheep)

Àgùtàn
Ipò ìdasí
Ọ̀sìn
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Ẹgbẹ́: Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò: Oníka-dídọ́gba
Ìdílé: Bovidae
Subfamily: Caprinae
Ìbátan: Ovis
Irú:
O. aries
Ìfúnlórúkọ méjì
Ovis aries
Synonyms

Ovis guineensis Linnaeus, 1758
Ovis strepsiceros Linnaeus, 1758

Àwọn Àgùtàn (Ovis aries) jẹ́ àwọn ẹranko afọ́mọlọ̀mú tí wọ́n sì ma ń tún ónjẹ wọn pọ̀ jẹ lẹ́yìn tí wọ́n bá ti jẹun tán. Bákan náà ni wọ́n sì tún jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin tí wọ́n ma ń jẹ̀ kiri. Ẹ̀wẹ̀, wọ́n tún jẹ́ ẹran ọ̀sìn abẹ́lé.[1]



  1. Amelinckx, Andrew (2017-12-22). "6 Fun Facts About Sheep You Might Not Know". Modern Farmer. Archived from the original on 2018-12-15. Retrieved 2018-12-11.