Èdè Shíkọmọ
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Shikomor)
Èdè Kòmórò | |
---|---|
Shíkọmọ | |
Sísọ ní | Comoros àti Mayotte |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 1993 |
Agbègbè | Káàkiri Comoros àti Mayotte; bákannáà ní Madagascar àti Réunion |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 700,000 |
Èdè ìbátan | |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | variously: zdj – Ngazidja dialect wni – Ndzwani (Anjouani) dialect swb – Maore Comorian wlc – Mwali dialect |
Èdè Shíkọmọ (Shikomor) tàbí èdè Kòmórò ni èdè tó gbalẹ̀ jùlọ ní ní Kòmórò (àwọn erékùṣù olómìnira ní Òkun Ìndíà, nítòsí Mòsámbíkì àti Madagáskàr) àti ní Mayotte. Ó jẹ́ ẹ̀ka èdè Swahili sùgbọ́n ipa púpọ̀ lọ́dọ̀ èdè Lárùbáwá ju Swahili lọ. Erékùṣù kọ̀ọ̀kan ní ọ̀nà ìsọ èdè ti wọn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; ti Anjouan únjẹ́ Shindzuani, ti Mohéli Shimwali, ti Mayotte Shimaore, ati ti Grande Comore Shingazija. Kò sí álfábẹ́tì oníbiṣẹ́ kankan fún un títí ọdún 1992, sùgbọ́n ọnà-ìkọ́ Lárùbáwá àti Latin únjẹ́ lílò fun.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |