Slimcase
Slimcase | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Oluwafemi Oladapo |
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kẹjọ 1982 Lagos State, Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Ikorodu, Lagos |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2017 – present |
Associated acts |
Ọjọ́ kejìlélógún, oṣù kẹ́jọ, ọdún 1982 ni wọ́n bí Olúfẹ́mi Ọládàpọ̀ tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Slimcase,[1] olórin, akọrin, akígbe, àti òṣẹ̀ré ni ó jẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[2][3]. Ohun tí ó sọ ọ́ di ìlú-mọ̀-ọ́-ká ní àwọn orin tí ó kọ pẹ̀lú àwọn olórin ẹgbẹ́ rẹ̀ bí i: orin D'banj ,'Issa Banger'[4][5] àti 'Gucci Snake', láti ọwọ́ Wizkid[6] pẹ̀lú ijó tí ó gbòdekan nígbà náà, tí àwọn ènìyàn ń pè ní 'shaku shaku'[7][8][9] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórin lórílè-èdè Nàìjíríà bí i Wizkid, Tiwa Savage,[10] Yemi Alade,[11] Mr Eazi, 2Babaló ti bá kọrin.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìlú korodu ní ìpínlẹ̀ Èkó ní àwọn òbí Olúwafẹ́mi Ọládàpọ̀ bí i sí ní ọjọ́ kejìlélógún, oṣù kẹ́jọ, ọdún 1982[12][13]. Ìlú Èkó ní ó ti gba ìwé èrí alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti girama, ní bi tí ó ti parí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama. [14]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2018, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú olórin gbajúgbajà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Idowest nínú orin rẹ 'Shepeterri' [15]
Ní ọdún 2018, wọ́n kà á kún ẹni tí àmì-èye tọ́sí fún The Headies gẹ́gẹ́ bí olórin tàka-súfèé tó dáa jù àti olórin tuntun tó dáńgájíá ní Nigeria Entertainment Awards
Ní ọdún 2018, ó gba àmì-ẹ̀yẹ orin tó dara jù tí olórin méjì kọ pọ̀ City People Entertainment Awards[16]
Kíkà kún ẹni tí Àmì-ẹ̀yẹ tọ́sí àti Àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2018 | The Headies | Best Street-Hop Artiste | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [17] | |
Nigeria Entertainment Awards | Best New Act | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [18] | ||
City People Entertainment Awards | Best Collabo | "Himself" | Gbàá | ||
City People Entertainment Awards | Best Collabo | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [19] |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Davis Exotic Homes unveils Slimcase, Mercy Alexander as brand ambassadors". 24 August 2021. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "Real Deal Experience Hits Lagos With Mr. Real, Slimcase". 18 August 2018. Archived from the original on 8 September 2021. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "Nigerians Troll Slimcase For Cardi B And Rihanna Collaboration". 5 January 2019. Archived from the original on 3 September 2021. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "D’banj Teams Up With Street Champs For ‘Issa Banger’, Watch The Slimcase & Mr Real – Assisted Video". 2 December 2018. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "Chemistry between D’banj and I very profitable – Slimcase". 22 June 2019. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "Listen to Wizkid's Catchy New Track 'Gucci Snake' Featuring Slimcase". 13 November 2018. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "How I made Shaku Shaku dance popular –Slimcase". 20 April 2018. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "I’m the vehicle to drive shaku shaku to the world- Slimcase". 17 April 2018. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "Meet the 'Oshozondi' Shaku Shaku champion, who dreams of teaching the dance to Beyonce, Nicki Minaj, Usher". 8 August 2021. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "Watch Visuals For Enimoney’s – “Diet” Featuring Reminisce, Tiwa Savage And Slim Case". 26 March 2018. Archived from the original on 5 August 2021. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "YEMI ALADE GOES FOR STREET CREDIBILITY WITH SLIMCASE – BRAINEE ASSISTED ‘YAJI’". 4 March 2019. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "Slimcase". Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "For ten years I earned N15,000 per month but I now charge N1m per show –Slimcase". 10 March 2018. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "I’m in a complicated relationship –Slimcase". 22 June 2019. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "HOW THE SONG SHEPETERI SHOT ME TO LIMELIGHT – MUSIC STAR, SLIMCASE". 3 December 2018. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "WINNERS EMERGE @ 2018 CITY PEOPLE MUSIC AWARDS". 3 November 2018. Retrieved 28 March 2021.
- ↑ "Headies 2018: Full list of nominees". The punch newspaper. Retrieved 13 April 2018.
- ↑ "Nigerian Entertainment Awards 2018: Complete list of nominees". Music In Africa. Retrieved 12 September 2018.
- ↑ "#CPMA2018: CITY PEOPLE MUSIC AWARDS NOMINEES’ LIST OUT". 17 October 2017. Retrieved 28 March 2021.