Springbok

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Springbok
Male at Etosha National Park
Ipò ìdasí
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Ìdílé:
Subfamily:
Ìbátan:
Antidorcas

Sundevall, 1847
Irú:
A. marsupialis
Ìfúnlórúkọ méjì
Antidorcas marsupialis
(Zimmermann, 1780)
Subspecies
  • A. m. angolensis (Blaine, 1922)
  • A. m. hofmeyri (Thomas, 1926)
  • A. m. marsupialis (Zimmermann, 1780)
Synonyms

springbok jẹ́ alábọ́dé ẹtu tí wọ́n ń rí ní gúúsù áfríkà àti gúúsù-wọ̀orùn áfríkà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Antidorcas, Jẹ́mánì onímọ̀ ẹranko Eberhard August Wilhelm von Zimmermann ló kọ́kọ́ ṣe àpèjuwe ọmọ ẹbí Bovidae yìí ní ọdún 1780. Ẹ̀yà méta ẹranko yìí tí di mímọ̀. Ẹtu èyí tẹ́ẹ́rẹ́ tẹ́sẹrẹ̀ gùn, springbok gùn tó 71 sí 86 cm (28 to 34 in) ní ìwọ̀n èjìká àti ìwúwosí láti 27 sí 42 kg (60 sí 93 lb). Akọ àti abo rẹ̀ ní ìho méjì tí ó yípo sẹ́yìn. Springbok yìí ma ń ní ojú funfun, ìlà dúdú láti ojú dé ẹnu, àwọ̀ pako fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ tí ó pupa díẹ̀ láti apá iwájú dé íbubu ìha ìdí rẹ̀.

Ara rẹ̀ ma ń yá gágá ní àfẹ̀mọ́jú àti àṣàalẹ́, springbok fọ́ọ̀mù àdàlù ìbálòpọ̀. Ní ìgàkan sẹ́yìn, springbok ti aṣálẹ Kalahari àti ti Karoo ma ń kóra wọn kọjá ní igbóẹgàn, lèyí tí à ń pè ní trekbokken.

Àkójọ àti ìtànkálẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

gerenuk, àwọn ẹ̀yà tí springbok lè jọ

Springbok jẹ́ ìkangbọ̀n ní ìdílé Antidorcas tí wọ́n sì gbe sí ẹbí Bovidae.[2] Eberhard August Wilhelm Zimmermann von onímọ̀ ẹranko ọmọ orílẹ̀ èdè Jemaní ni ó kọ́kọ́ ṣe àpèjúwe ẹranko yìí ní ọdún 1780. Zimmermann kó ìdílé Antilope (blackbuck) sí springbok.[3] Ní ọdún 1845, Carl Jakob Sundevall onímọ̀ ẹranko ọmọ orílẹ̀ èdè Sweden ló kó springbok Antidorcas,ìdílé tiẹ̀..[4]







Gazella



Blackbuck (Antilope cervicapra)





Nanger



Eudorcas






Springbok (Antidorcas marsupialis)



Gerenuk (Litocranius walleri)






Saiga (Saiga tatarica)



Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. http://www.iucnredlist.org/details/1676/0
  2. Àdàkọ:MSW3 Artiodactyla
  3. von Zimmermann, E.A.W. (1780) (in German). Geographische Geschichte des Menschen, und der Allgemein Verbreiteten Vierfüssigen Thiere: Nebst Einer Hieher Gehörigen Zoologischen Weltcharte. Leipzig, Germany: In der Weygandschen Buchhandlung. p. 427.  open access publication - free to read
  4. Sundevall, C.J. (1844). "Melhodisk öfversigt af Idislande djuren, Linnés Pecora" (in Swedish). Kungl. Svenska Vetenskapsakademiens Handlingar. 3: 271. http://www.biodiversitylibrary.org/item/182326#page/795/mode/1up.  open access publication - free to read