Tomi Odunsi
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Tómi Ọdúnsì)
Tómi Ọdúnsì | |
---|---|
Odunsi at the 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards | |
Ọjọ́ìbí | 24 May 1987 Ìpínlẹ̀ Ògùn |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian (1987–present) |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Gbajúmọ̀ fún | Tinsel |
Tomi Odunsi tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún oṣù Karùn-ún ọdún 1987 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olórin, òńkọrin tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ṣaléwá nínú eré onípele ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ti Tinsel.[1][2]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Tómi ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún oṣù Karùn-ún ọdún 1987 ní Ìpínlẹ̀ Ògùn. Ó lọ sílé ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè (linguistics) àti èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀, tí ó sì mú èdè Yorùbá ní iṣẹ́ àṣàyàn. [3] She premiered her debut single, "I Wan Blow", in April 2013 and performed it at the Oriental Hotel in August 2013.[4]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lára awọn àkọsílẹ̀ orin rẹ̀ tí ó gbajúmọ̀ ni:
- The Magic 2013 Christmas Theme Song[5][6]
- In the Music Movie soundtrack
- All the songs in her EP, Santacruise
- Superwomen episode on Moments with Mo with Mo Abudu
- Urban Lounge TV show theme song
Ipa rẹ̀ nínú tíátà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Olúrónbí: The Musical[7][8] 1 & 2: Sope (support). Aboriginal Productions.
- Oluronbi: The Musical[9][10] 3: Ope (support). Aboriginal Productions
- Fractures:[11][12] Toju (Lead). Aboriginal Productions
- Rú bí ewé:[13][14][15] Cup (Support). Paws Productions.
- Saro: The Musical:[16][17][18] Ronke (Support). TerraKulture BAP Productions
Àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ohun mìíràn tí Tómi tún ń ṣe ni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ CGT Media Ltd,[19] African entertainment and media company.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Tinsel star, TOMI ODUNSI speaks on her ambassadorial appointment, career and music". Encomium Magazine.
- ↑ "i am not a sex symbol shalewa of Tinsel". The Express Tribune.
- ↑ "I’ve been robbed of my privacy –Tomi Odunsi". The Punch – Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2 January 2015. Retrieved 22 October 2020.
- ↑ Our. "African Movie Channel is dedicated to best of Nollywood movies".
- ↑ "BN Exclusive: Africa Magic's Official Christmas Theme Song 2013 | Written & Performed by Tomi Odunsi – BellaNaija". www.bellanaija.com. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ "AUDIO: AfricaMagic’s Official Christmas Theme Song 2013 – Written & Performed by Tomi Odunsi – TalkMedia Africa". talkmediaafrica.com. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ "OLURONBI:THE MUSICAL | 360Nobs.com". www.360nobs.com. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ "Oluronbi Musical". Linda Ikeji's Blog. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ ""OLURONBI" The AFRICAN DANCE MUSICAL.". The Wild Black Child. 23 September 2009. https://thewildblackchild.wordpress.com/2009/09/23/oluronbi-the-african-dance-musical/.
- ↑ "Omawumi, Yinka Davies, Timi, Ireti Doyle and other talented stars revive OLURONBI – BellaNaija". bellanaija.com. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ "Aboriginal Productions out with Fractures – Vanguard News". Vanguard News. 19 February 2010. https://www.vanguardngr.com/2010/02/aboriginal-productions-out-with-fractures/.
- ↑ Editor, Online (28 January 2017). "Aboriginal Theatre's Fractures in Retrospect". THISDAYLIVE. https://www.thisdaylive.com/index.php/2017/01/29/aboriginal-theatres-fractures-in-retrospect/.
- ↑ "Rubiewe Archives | 360Nobs.com". www.360nobs.com. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ "'Rubiewe': The African 'Beauty & The Beast' on stage May 27, 29 » YNaija". YNaija. 16 May 2012. https://ynaija.com/rubiewe-the-african-beauty-the-beast-on-stage-may-27-29/.
- ↑ "360Fresh: Jaygo – Rubiewe | 360Nobs.com". www.360nobs.com. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ Adiele, Chinedu. "Saro The Musical: A broadway style theater production live on stage this Easter". http://www.pulse.ng/lifestyle/events/saro-the-musical-a-broadway-style-theater-production-live-on-stage-this-easter-id3612725.html.
- ↑ Editor, Online (27 August 2017). "Saro the Musical Premieres in London, Gets Standing Ovation". THISDAYLIVE. https://www.thisdaylive.com/index.php/2017/08/27/saro-the-musical-premieres-in-london-gets-standing-ovation/.
- ↑ "SARO The Musical". saroterrakulture.blogspot.com.ng. Retrieved 2 April 2018.
- ↑ "CGT Management (@cgtmgt) • Instagram photos and videos". instagram.com. Retrieved 2 April 2018.