Tejumade Alakija

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Omoba
Tejumade Alakija
Ọjọ́ìbí17 May 1925
Nigeria
AláìsíAugust, 2013
University College Hospital, Ibadan
Orílẹ̀-èdèNigeria
TitleOmoba

Tẹjúmádé Alákijà (bíi ni ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1925) jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má jẹ́ olórí fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[1]. Bàbá Tẹjúmádé jẹ́ ọba ní ìlú Ifẹ̀. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Oxford University, ó sì gboyè jáde gẹ́gẹ́ bí olùkó. Ó gboyè Pro-Chancellor fún ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Abuja láti ọdún 1993 títí di ọdún 1997[2]. Alákijà kú ní ọdún 2013 ní ilé ìwòsàn University College Hospital ní ìlú Ibadan.[3][4]

Awon Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]