Tope Oshin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Tope Oshin
Tope Oshin.jpg
Oshin in 2015
Ọjọ́ìbíTemitope Aina Oshin
Oṣù Kẹfà 10, 1979 (1979-06-10) (ọmọ ọdún 41)
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaLagos State University, Nigeria
Colorado Film School, Community College of Aurora, Denver
Met Film School, London.
Iṣẹ́Filmmaker
Ìgbà iṣẹ́1996-present
Notable workShuga
Up North (film)[1]
New Money (2018 film)
The Wedding Party 2
Journey to Self
Tinsel (TV series)
Fifty
Websitetopeoshin.info

Tope Oshin je adarí fíìmù ni Nàìjíríà, ó sì jẹ ìkan laarin awọn gbajúmọ̀ nínú ẹ̀ka eré ni odun 2019.[2] Ní ọdún 2015, Ìwé ìròyìn Pulse sọ wí pé ó wà láàrin àwọn obìnrin mẹsan tí ó ṣe adarí eré tí ó yẹ kí àwọn èèyàn mọ.[3] Ní ọdún 2018, ní ìrántí oṣù obìnrin, OkayAfrica yẹ́ Tope sì gẹ́gẹ́ bí ìkan lára àwọn Okay100 Women.[4]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Ilorin níbi tí ó tí ká economics, ṣùgbọ́n kò parí níbẹ̀, ó padà parí ni ilẹ̀ Ẹ̀kọ́ gíga tí Lagos State University níbi tí ó tí gboyè nínú Theatre Art.[5] Ó tesiwaju nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ èrè sise nígbà tí ó lọ sí Colorado Film School ni Community College of Aurora tí ó wà ní Denver àti Met Film School ní London.[6] Tope jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tẹ́lẹ̀ fún Talents Durban[7] àti Berlinale Talents.[8][9]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tope jẹ́ òṣèré fún ọdún méjìlá, ó sì ti fara hàn nínú àwọn eré bíi Relentless. Ó ṣe ìgbà kejì adarí fún eré The Apprentice Africa.[5] Ó ti ṣe adarí fún àwọn eré bíi In line,[10] Ireti,[11] , New Horizon,[12] Hush, Hotel Majestic, Tinsel àti MTV Shuga.[13] Óun ni ó ṣe adarí fún àwọn eré gbajúmọ̀ bíi Up North[14][15] àti New Money[16][17]. Ní oṣù Kejìlá ọdún 2015, eré Fifty[18] tí ó ṣe pá #20 million ni ọ̀sẹ̀ tí ó jáde.[19] Ere The wedding party tí ó ṣe ní ọdún 2018, jẹ́ ère tí ó tà ju ni Nàìjíríà ni odun náà.[20] Ní ọdún 2016, ó ṣe eré ìtàn, Amaka’s Kin [21] ni ìrántí gbajúmò òṣèré Amaka Igwe tí ó kú ní ọdún 2014.[22] Ní ọdún 2017, ó ṣe ère ìtàn Nigeria - Shooting it like a woman.[23][24] Ní ọdún 2018, ó ṣe eré We Don't live here anymore[25] [26]fun àwọn TIERs.[27][28] Eré náà kò ṣe wò lórí sinema nítorí àwọn àríyànjiyàn[29] tí ó wà pẹ̀lú eré náà. Ó ti ṣe ère fún oríṣiríṣi fíìmù àti eré orí telefisionu bíi MTV Shuga[30][31] apá kẹrin[32] àti apá kẹfà.[33] Láti ọdún 2015, ní o ti wa láàrín àwọn adájọ́ fún International Emmy Award.[34]

Ebun[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀wọ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • OkayAfrica Okay100Women 2017 Honoree[35]
 • Excellence in The Creative Industries Award - Sisi Oge Awards 2018[36]
 • Distinguished Alumni Medal of Honor 2016 - In-short film festival[37]
 • African Woman In Film Award 2015 by African Women Development Fund[38]


Year Award Category Result
2018 Best of Nollywood Awards Best Director of The Year (We Don’t Live Here Anymore) Gbàá [39]
2018 Best of Nollywood Awards Best Movie of The Year (We Don’t Live Here Anymore)

Gbàá

2017 City People Entertainment Awards Best Director Of The Year Gbàá
2016 Best of Nollywood Awards Best Documentary (Amaka’s Kin) Gbàá
2016 Womens Only Entertainment Film Festival Best International Female Director (Ireti) Gbàá
2016 Womens Only Entertainment Film Festival Best International Short Film Gbàá
2016 Nigerian Broadcast Media Awards Best TV Program Director (Tinsel) Gbàá

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. https://tribuneonlineng.com/tope-oshin-sets-the-pace-for-female-directors-as-she-goes-up-north/
 2. https://ynaija.com/ynaija-presents-the-100-most-influential-nigerians-in-film-in-2019/
 3. "9 Nigerian female movie directors you should know". Pulse. Retrieved 20 September 2016. 
 4. "TOPE OSHIN-OkayAfrica's 100 Women". OkayAfrica. Retrieved 1 March 2018. 
 5. 5.0 5.1 "Amaka Igwe encouraged me to go into directing —Nollywood star Tope Oshin Ogun". The Nation. Retrieved 20 September 2016. 
 6. "Hooray for Nollywood: how women are taking on the world's third largest film industry". The Irish Times. November 16, 2016. http://www.irishtimes.com/culture/film/hooray-for-nollywood-how-women-are-taking-on-the-world-s-third-largest-film-industry-1.2870650. Retrieved December 15, 2016. 
 7. "Tope Oshin - The Rise Of A Female Filmmaker". Omenka Online. Retrieved 13 October 2016. 
 8. "Tope Oshin - Berlinale Talents". 
 9. "Four For Berlinale Talents". ThisDay. http://www.pressreader.com/nigeria/thisday/20150222/282157879692937. Retrieved 22 February 2015. 
 10. "InLine-Tope Oshin's Amazing Film". TNS Nigeria. https://tns.ng/line-tope-oshin-many-wont-see-toni-kan/. 
 11. "BFI Press release - Beyond Nollywood showcases New Nigerian Cinema 2016". http://www.bfi.org.uk/sites/bfi.org.uk/files/downloads/bfi-press-release-beyond-nollywood-showcases-new-nigerian-cinema-2016-11-04.pdf. 
 12. "EbonyLifeTV launches powerful short film against domestic violence". http://ebonylifetv.com/2014/03/08/ebonylife-tv-launches-new-horizons-a-powerful-short-film-against-domestic-violence/. 
 13. "MTV Shuga Season 6 launches in Africa". The Net NG. February 23, 2018. http://thenet.ng/mtv-shuga-season-6-launches-africa-lagos-premiere/. Retrieved February 23, 2018. 
 14. http://culturecustodian.com/tope-oshins-up-north-is-coming-to-netflix-this-october/
 15. "Banky W to lead cast for Tope Oshin's Up North". XploreNollywood. 
 16. "New Money (2018)". IMDB. 
 17. "New Money (2018)". IMDB. 
 18. ""Fifty" producer shares the key to becoming a successful filmmaker". Pulse. Retrieved 20 September 2016. 
 19. "Nigerian movie breaks box office record, makes N20m in holiday weekend". Pulse. 30 December 2015. Retrieved 20 September 2016. 
 20. "The Wedding Party 2 - Sequel becomes Highest Grossing Nollywood Movie Of all Time". Pulse. January 23, 2018. http://www.pulse.ng/entertainment/movies/the-wedding-party-2-is-the-highest-grossing-nollywood-movie-id7879784.html. Retrieved January 23, 2018. 
 21. "BFI Press release - Beyond Nollywood showcases New Nigerian Cinema 2016". http://www.bfi.org.uk/sites/bfi.org.uk/files/downloads/bfi-press-release-beyond-nollywood-showcases-new-nigerian-cinema-2016-11-04.pdf. 
 22. "Tope Oshin to debut documentary on women of Nollywood". Pulse. Retrieved 20 September 2016. 
 23. "BBC World Service - The Documentary, Nigeria: Shooting It Like A Woman". BBC World Service. 
 24. "Ladies Calling The Shots - Book on Female Directors For Launch in Lagos". July 17, 2015. http://pmexpressng.com/ladies-calling-shots-book-female-directors-launch-lagos. Retrieved July 17, 2015. 
 25. https://www.pulse.ng/entertainment/movies/we-dont-live-here-anymore-watch-trailer-for-new-nigerian-gay-themed-movie/qeq4svd
 26. "Tope Oshin's New Film - We Don't Live Here Anymore". YNaija. 
 27. http://2018.africa-in-motion.org.uk/festival/glasgow/event/310.html
 28. https://ynaija.com/bon-awards-2018-tope-oshins-we-dont-live-here-anymore-wins-best-movie-of-the-year/
 29. https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/10/27/tope-oshins-we-dont-live-here-anymore-rattles-nollywood/
 30. "Shuga(TV Series) - Full Cast & Crew". 
 31. https://www.thisdaylive.com/index.php/2019/03/29/tope-oshin-to-produce-new-mtv-shuga-series/
 32. https://www.imdb.com/title/tt2577388/fullcredits
 33. https://www.imdb.com/title/tt2577388/fullcredits/?ref_=tt_ov_st_sm
 34. "EbonyLife hosts Emmy Awards Judging Event". July 17, 2015. http://thenationonlineng.net/ebonylife-tv-hosts-emmy-awards-judging-event/. Retrieved July 17, 2015. 
 35. https://100women.okayafrica.com/film-tv-articles/2018/2/28/tope-oshin
 36. https://www.bellanaija.com/2018/04/sisi-oge-2018-winner/
 37. https://judithaudu.tumblr.com/post/154696115572/we-got-awarded-a-medal-of-honor-at-in-short-film
 38. http://awdf.org/nigerian-tope-ogun-wins-awdf-women-in-film-award/
 39. https://therustintimes.com/2018/12/10/we-dont-live-here-anymore-bags-5-awards-at-the-best-of-nollywood-awards/