Uko Nkole
Ìrísí
Uko Ndukwe Nkole | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20/10/ 1975 Abam Onyereubi, Arochukwu, Abia State |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (Nigeria) (PDP) |
Occupation | Legislature |
Profession | Registered /Fellow Nigerian Institute Of Town Planners/Politician |
Uko Ndukwe Nkole (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹwàá ọdún 1975 ní Ozu Abam Arochukwu, Ìpínlẹ̀ Ábíá) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olóṣèlú Nàìjíríà àti ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmò asofin Nàìjíríà.[1] Nkole ni aṣojú Arochukwu/Ohafia ní ilé ìgbìmò asofin kékeré.[2]
Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Uko Ndukwe Nkole ní ọjọ́ ogún oṣù kẹwàá ọdún 1975 sínú ìdílé Olóyè Emmanuel Ndukwe Nkole àti Madam Nkole. Bàbá rẹ̀ jẹ́ olùdarí àgbà ní Banki àpapò ti Nàìjíríà,[3] Nkole lọ ilé-ìwé Government College ti ìlú Umuahia àti Ovukwu Secondary school, níbi tí ó ti ka ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì rè. Ó tẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní e Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà, Nsukka láti gbà àmì-ẹyẹ nínú ìmò jiograpi ní ọdun 1999.
Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Emeruwa, Chijindu (2020-07-25). "Abia PDP berates lawmaker, Uko Nkole, threatens to recall him". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-21.
- ↑ "National Assembly | Federal Republic of Nigeria". www.nassnig.org. Archived from the original on 29 November 2020. Retrieved 27 April 2020.
- ↑ Nwosu, Uche. "Federal Lawmaker Loses Father At Yuletide". Leadership Newspaper. Retrieved 27 April 2020.