Uko Nkole

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Uko nkole)
Uko Ndukwe Nkole
Member of the House of Representatives of Nigeria
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20/10/ 1975
Abam Onyereubi, Arochukwu, Abia State
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (Nigeria) (PDP)
OccupationLegislature
ProfessionRegistered /Fellow Nigerian Institute Of Town Planners/Politician

Uko Ndukwe Nkole (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹwàá ọdún 1975 ní Ozu Abam Arochukwu, Ìpínlẹ̀ Ábíá) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olóṣèlú Nàìjíríà àti ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmò asofin Nàìjíríà.[1] Nkole ni aṣojú Arochukwu/Ohafia ní ilé ìgbìmò asofin kékeré.[2]

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Uko Ndukwe Nkole ní ọjọ́ ogún oṣù kẹwàá ọdún 1975 sínú ìdílé Olóyè Emmanuel Ndukwe Nkole àti Madam Nkole. Bàbá rẹ̀ jẹ́ olùdarí àgbà ní Banki àpapò ti Nàìjíríà,[3] Nkole lọ ilé-ìwé Government College ti ìlú Umuahia àti Ovukwu Secondary school, níbi tí ó ti ka ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì rè. Ó tẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní e Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà, Nsukka láti gbà àmì-ẹyẹ nínú ìmò jiograpi ní ọdun 1999.

Àwọn Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Emeruwa, Chijindu (2020-07-25). "Abia PDP berates lawmaker, Uko Nkole, threatens to recall him". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-21. 
  2. "National Assembly | Federal Republic of Nigeria". www.nassnig.org. Archived from the original on 29 November 2020. Retrieved 27 April 2020. 
  3. Nwosu, Uche. "Federal Lawmaker Loses Father At Yuletide". Leadership Newspaper. Retrieved 27 April 2020.