Jump to content

Umar Saidu Doka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Umar Saidu Doka
Member of the
House of Representatives of Nigeria
from Niger
In office
2019-2023
ConstituencyShiroro/Rafi/Munya
Àwọn àlàyé onítòhún
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
OccupationPolitician

Umar Saidu Doka je oloselu omo Naijiria . O ṣiṣẹ bi ọmọ ẹgbẹ ti o nsójú Shiroro/Rafi/Munya ni ile ìgbìmò aṣòfin àgbà . [1] [2]

Igbesi aye ibẹrẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Umar Saidu Doka ni won bi ni 1965.

Umar ni wón yan labẹ ẹgbẹ òṣèlú All Progressive Congress (APC) sinu ile igbimo asofin agba lodun 2019 lati soju agbegbe re ni ile igbimo asofin. [3]