Wàsíù Àlàbí Pasuma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Wasiu Alabi Pasuma
Ọjọ́ìbí(1967-11-27)27 Oṣù Kọkànlá 1967
Mushin, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian,Georgia[1][2]U.S.A
Iṣẹ́film actor
fuji musician Hip hop musician
Àwọn ọmọ10 [2 males, 8 females]

Wọ́n bí Wasiu Àlàbí Pasuma ní (November 27, 1967) sí Mushin ní ìpínlẹ̀ Èkó, tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Kwárà òun náà ni wọ́n tún ń pè ní "Ògánla". Ó jẹ́ òṣèré, ọ̀kọrin Fújì ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjìríà.[3]


[4][5]

iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Pasuma di gbajú-gbajà olórin Fújì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà tí ó ṣe àwo orin tó sọọ́ di ìlú-mọ̀ọ́ká tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Recognition" ní ọdún 1993.[6]  Ó ti ṣe àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ orin pẹ̀lú àwọn oríṣiríṣi olórin bíi: Bola Abimbola àti King Sunny Ade. Bákan náà ni ó ti kópa nínú eré orí-ìtàgé ilẹ̀ Nàìjíríà bíi: Ìyànjẹ àti Aléni báre.[7]

Ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹ́jọ ọdún 2015 (Sept.6, 2015), Pasuma gba àmì ẹ̀yẹ olórin ìbílẹ̀ tó dára jùlọ Nigeria Entertainment Awards mọ́ àwọn olórin Gẹ̀ẹ́sì bíi: Ọlámídé, Phyno, Flavor [8]. Wọ́n tún yàán fún àmì ẹ̀yẹ 'olórin tí kìí ṣe olórin ẹ̀sìn Islam , tó kópa tó pọ̀ nínú àwo orin ẹ̀sin  Islam' ní ọ́dún 2016, òun pẹ̀lú King Saheed Òṣùpá, Súlè Àlàó Malaika, Shefiu Àlàó, Taye Currency, àti Muri Thunder.

Àwọn àwo orin rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alhaji Wasiu Alabi Pasuma ti gbé àwo orin Fújì tó lé ní ọgbọ̀n 30 jáde lạ́ti ọdún 1993 [9]. Àwọn àwo orin rẹ̀ nìwọ̀nyí:

 • Recognition
 • Choice
 • Orobokibo
 • computer
 • The man
 • Confidence
 • London experience
 • London Scope
 • Afican Puff Daddy
 • Entertainer
 • American
 • Extervanganzer
 • Desperado
 • High and joker (2in1)
 • Judgment
 • Unique and superior (2in1)
 • Fuji Motion
 • Maintain and Sustain (2in1)
 • Intiator
 • Importer and exporter (2 in 1)
 • Stability
 • In and out
 • Brain box and Stadium (2in1)
 • Infinity
 • Role Model
 • Feel it
 • Ability
 • Yankee Party Time
 • Sure pass
 • Influential
 • Purity
 • December tonic
 • Torin tilu
 • My World (Hip-hop album)
 • Me, Myself and I
 • Undefeated
 • Compatibility
 • Goodness and Mercy
 • Wisdom and Maturity

Àwọn orin àjọkọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Iseju Meji (Ft 9ice)
 • Whyne am
 • Kowale
 • Change
 • Action (ft Olamide)
 • Quality
 • Olorun Oje (ft Q dot)
 • Am on fire (ft Phyno)
 • Labe igi (ft Oritshe Femi)
 • Oruka
 • Our Lagos (ft Patoranking)
 • Ife (Ft Tiwa Savage)
 • ogede ti pon
 • Abo
 • Oganla (ft Olamide & Lil Kesh)

Àwo fídíò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Title Director Ref
2016 Aiye Miami (Remix) As featured artist H2G Films [10]

̀Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Patricia, Uyeh (May 2, 2018). "http://allure.vanguardngr.com/2018/04/fuji-singer-pasuma-gets-honoured-georgia-state-citizenship/". Vanguardngr.com. http://allure.vanguardngr.com/2018/04/fuji-singer-pasuma-gets-honoured-georgia-state-citizenship/. Retrieved April 7, 2018. 
 2. David (March 21, 2018). "http://www.informationng.com/2018/03/fuji-musician-pasuma-awarded-honorary-citizenship-of-georgia-usa-photos.html". Informationng.com. http://www.informationng.com/2018/03/fuji-musician-pasuma-awarded-honorary-citizenship-of-georgia-usa-photos.html. 
 3. NaijaGists http://naijagists.com/pasuma-alabi-odetola-celebrates-45th-birthday-today-biography-incl/. Retrieved 21 December 2016.  Missing or empty |title= (help)Missing or empty |title= (help)
 4. "Pasuma vs Saheed Osupa, who is taking over Fujidom". The Sun Newspaper. Retrieved 21 January 2015. 
 5. "Fuji and its Pop Condiments, Articles". thisdaylive.com. Retrieved 21 January 2015. 
 6. "On new logo, Kwara flaunts its tourist attractions". The Punch. Retrieved 21 January 2015. 
 7. "Wasiu Ayinde Rejects Pasuma At His "K1 Live Unusual" Concert, Saheed Osupa, Obesere, Ayuba, 2Face, Olamide To Grace Show". nigeriatell.com. Retrieved 21 January 2015. 
 8. Kayode, Badmus. "http://thenet.ng/pasuma-defeats-olamide-and-phyno-to-emerge-indigenous-artist-of-the-year/". The net.ng. Kayode. http://thenet.ng/pasuma-defeats-olamide-and-phyno-to-emerge-indigenous-artist-of-the-year/. Retrieved September 7, 2015. External link in |title= (help)
 9. http://ajele1.blogspot.co.ke/2011/12/otunba-wasiu-ajibola-alabi-pasuma-all.html?m=1.+"http://ajele1.blogspot.co.ke/2011/12/otunba-wasiu-ajibola-alabi-pasuma-all.html?m=1". Ajele. Check date values in: |access-date= (help); External link in |title= (help); |access-date= requires |url= (help)
 10. "Music Video Lace – Aiye Miami @knx9ja.tk (Remix) feat. Reekado Banks & Pasuma". Pulse.com.gh. David Mawuli. Retrieved 8 February 2016.