Wally Adéyẹmọ
Ìrísí
Wally Adéyẹmọ | |
---|---|
Official portrait, 2021 | |
15th United States Deputy Secretary of the Treasury | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga March 26, 2021 | |
Ààrẹ | Joe Biden |
Secretary | Janet Yellen |
Asíwájú | Justin Muzinich |
President of the Obama Foundation | |
In office August 1, 2019 – March 25, 2021 | |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Valerie Jarrett |
United States Deputy National Security Advisor for International Economics | |
In office 2015–2016 | |
Ààrẹ | Barack Obama |
Asíwájú | Caroline Atkinson |
Arọ́pò | Daleep Singh (2021) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Adewale O. Adeyemo 20 Oṣù Kàrún 1981 Ibadan, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | American |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
Education |
Adéwálé "Wally" Adéyẹmọ (wọ́n bí i lọ́dún 1981)[1] jẹ́ Ààrẹ àkọ́kọ́ fún àjọ-aṣàánú, Obama Foundation tí Ààrẹ àná orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Barack Obama dá sílẹ̀. [2] During the Obama Administration, Adéyẹmọ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí igbákejì olúdámọ̀ràn lórí ètò àbò fún àjọ ètò ọ̀rọ̀-ajé àgbáyé,International Economics lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 2015 sí 2016, bẹ́ẹ̀ náà òun ni igbá-kejì ọ̀gá àgbà ti National Economic Council.[3]
Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adéyẹmọ dàgbà sí Los Angeles, California.[4] Ó kàwé gboyè Bachelor of Arts láti University of California, Berkeley àti Juris Doctor láti Yale Law School.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Adewale Adeyemo: President of Obama Foundation". Leadership. August 11, 2019. Retrieved November 29, 2020.
- ↑ "Obama Foundation Announces Wally Adeyemo as President". Obama Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-30.
- ↑ "Statement by the President on the Selection of Adewale Adeyemo as Deputy National Security Advisor". whitehouse.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-12-15. Retrieved 2020-11-30.
- ↑ "Board of Trustees". Demos (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-30.
- ↑ Rachlin, Jill. "Wally Adeyemo". Reiss Center on Law and Security (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-06.