Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 10 Oṣù Kẹ̀wá
Ìrísí
- 680 – Ìjàgìdì Karbala: Hussain bin Ali, ọmọọmọ Ànábì Muhammad, jẹ́ bíbẹ́lórí látọwọ́ àwọn ajagun Kálífì Yazid I.
- 1780 – Ìjìnla Kàunkà ọdún 1780 pa àwọn ènìyàn 20,000-30,000 ní Kàríbẹ́ánì.
- 1975 – Papua New Guinea di ọmọ ẹgbẹ́ Àwọn Orílẹ̀-èdè Aṣòkan.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1813 – Giuseppe Verdi (àwòrán), Italian composer (al. 1901)
- 1930 – Harold Pinter, English playwright, Nobel laureate (al. 2008)
- 1979 – Mya Harrison, American singer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1875 – Aleksey Konstantinovich Tolstoy, Russian novelist, poet and dramatist (ib. 1817)
- 1985 – Orson Welles, American director and actor (ib. 1915)
- 2005 – Milton Obote, President of Uganda (ib. 1925)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |