Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 8 Oṣù Kẹ̀wá
Ìrísí
Ọjọ́ 8 Oṣù Kẹ̀wá: Ọjọ́ Ìlọ́mìnira ní Kroatíà (1991)
- 1582 – Nítorí ṣíṣe ìmúlò Kàlẹ́ndà Gregory ọjọ́ yìí kò wáyé nínú ọdún yìí ní Italy, Poland, Portugal àti Spain.
- 1912 – Ogun ará Bálkánì Àkọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀: Montenegro pe ogun ti Turkey.
- 1967 – Olórí Ogun Àìjáwọ́ Che Guevara àti àwọn èyàn rẹ̀ jẹ́ gbígbámú ní Bolivia.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1895 – Juan Perón, Ààrẹ ilẹ̀ Argentina (al. 1974)
- 1919 – Kiichi Miyazawa, Alákóso Àgbà 78k ilẹ̀ Japan (al. 2007)
- 1941 – Jesse Jackson (fọ́tò), àlufáà àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1869 – Franklin Pierce, Ààrẹ 14k àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà (ib. 1804)
- 1962 – Solomon Linda, akọrin àti adáorin ará Gúúsù Áfríkà (ib. 1909)
- 1992 – Willy Brandt, Kánsélọ̀ ilẹ̀ Jẹ́mánì (ib. 1913)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |