Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 9 Oṣù Kẹ̀wá
Ìrísí
Ọjọ́ 9 Oṣù Kẹ̀wá: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Ùgándà
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1892 – Ivo Andrić, olùkọ̀wé ará Yugoslavia (al. 1975)
- 1906 – Léopold Sédar Senghor (fọ́tò), akọewì àti olóṣèlú ará Senegal (al. 2001)
- 1940 – John Lennon, olórin ará Brítánì (The Beatles) (al. 1980)
- 1966 – David Cameron, Alákóso Àgbà Brítánì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1806 – Benjamin Banneker, atòràwọ̀ ará Amẹ́ríkà (ib. 1731)
- 1967 - Che Guevara, olùjídìde ará Argentina (ib. 1928)
- 1968 – Pierre Mulele, olùjídìde ará Kóngò (ib. 1929)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |