Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 11 Oṣù Kínní
Ìrísí
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1638 – Nicolas Steno (àwòrán), onímọ̀ jẹọ́lọ́jì ará Dẹ́nmárkì (al. 1686).
- 1755 – Alexander Hamilton, olóṣèlú àti ìkan nínú àwọn Baba Afilọ́lẹ̀ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (al. 1804).
- 1971 – Mary J. Blige, akọrin ará Amẹ́ríkà.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1928 – Thomas Hardy, olùkọ̀wé ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1840).
- 1966 – Lal Bahadur Shastri, Alákóso Àgbà kẹta orílẹ̀-èdè Índíà (ib. 1904).
- 1988 – Isidor Isaac Rabi, onímọ̀ físíksì àti ẹlẹ́bùn Nobel (ib. 1898).
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |