Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 15 Oṣù Kínní
Appearance
- 1966 – Ìfipágbàjọba ológun ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà fún ìgbà àkọ́kọ́.
- 1970 - Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà wá sópin
- 2001 – Wikipedia, Wiki ọ̀fẹ́ àkóónú ẹnsiklopẹ́díà bẹ̀rẹ̀ lórí Internet.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1906 – Aristotle Onassis, ọmọ Gríìkì oníṣòwò (al. 1975)
- 1918 – Gamal Abdal Nasser, Ààrẹ ilẹ̀ Egypt (al. 1970)
- 1929 - Martin Luther King, Jr. (fọ́tò)), alákitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 1968)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1919 – Rosa Luxemburg, kọ́múnístì ará Jẹ́mámì (ib. 1870)
- 1966 - Abubakar Tafawa Balewa, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1912)
- 1966 - Ahmadu Bello, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1910)
- 1966 - Ladoke Akintola, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1910)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |