Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 17 Oṣù Kínní
Ìrísí
Ọjọ́ 17 Oṣù Kínní: Ọjọ́ Martin Luther King Jr. ní USA
- 2002 – Òkè Nyiragongo tújáde ní Kọ́ngọ 20 kilometres (12 mi) ní àríwá ìlú Goma, ó pa ilé 4,500 run, ó sì sọ àwọn ènìyàn bíi 120,000 di aláìnílé.
- 1991 – Àpapọ̀ ológun tí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà léwájú gbógun ti Iraq.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1927 – Eartha Kitt, akorin ati òṣeré ará Amẹ́ríkà (al. 2008)
- 1931 – James Earl Jones', òṣeré ará Amẹ́ríkà
- 1942 – Muhammad Ali, ajaẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà
- 1964 – Michelle Obama, Ìyáàfin Àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1961 – Patrice Lumumba, Alákóso Àgbà orílẹ̀-èdè Kóngò (ib. 1925)
- 2005 – Zhao Ziyang, Olórí ìjọba ilẹ̀ Ṣáínà (ib. 1919)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |