Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 22 Oṣù Kínní
Ìrísí
- 1824 – Àwọn Ashanti borí àwọn ajagun ará Brítánì ní Gold Coast.
- 1879 – Ogun Anglo àti Zulu: Ìjà Isandlwana – Àwọn ajagun Zulu borí àwọn ajagun ará Brítánì.
- 2006 – Evo Morales di Ààrẹ ilẹ̀ Bolivia, òhun ni ààrẹ ọmọ ilẹ̀ abínibí àkọ́kọ́.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1561 – Francis Bacon, amòye ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1626)
- 1788 – George Gordon Byron, Baron Byron 6k, akọewì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1824)
- 1891 – Antonio Gramsci, amòye ará Itálíà (al. 1937)
- 1931 – Sam Cooke (fọ́tò), akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 1964)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1922 – Fredrik Bajer, olóṣèlú àti ẹlẹ́bùn Nobel ará Dẹ́nmárkì (ib. 1837)
- 1922 – Camille Jordan, onímọ̀ mathimátíkì ará Fránsì (ib. 1838)
- 1973 – Lyndon B. Johnson, Ààrẹ 36k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (ib. 1908)
- 1994 – Telly Savalas, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1924)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |