Zulu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Zulus
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
10,659,309 (2001 census)[1]
Regions with significant populations
 Gúúsù Áfríkà
KwaZulu-Natal 7.6 million [1]
Gauteng 1.9 million [1]
Mpumalanga 0.8 million [1]
Free State 0.14 million [1]
Èdè

Zulu
(many also speak English, Afrikaans, Portuguese, or other indigenous languages such as Xhosa)

Ẹ̀sìn

Christian, African Traditional Religion

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Bantu · Nguni · Basotho · Xhosa · Swazi · Matabele · Khoisan

Zulu Àwon ènìyàn Zulu ni èyà tó pòjù ni orílè-èdè Gúúsù Áfríkà. A mò wón mó ìlèkè alárànbàrà àti agbòn pèlú àwon ñnkan gbígbé. Wón gbàgbó pé àwon jé ìran tó sè lára olóyè kan láti agbègbè Cóńgò, ni ñnkan egbèrún odùn mérìndínlógún séyìn ni won tèsíwájú sí Gúsú. Àwon ènìyàn Zulu gbàgbó nínú òrìsà tó ń jé Nkulunkulu gègé bí asèdá won òrishà yìí ko ní àjosepò pèlú ènìyàn béè ni kò ní ìfé sí ìgbé ayé kòòkan. Awon ènìyàn Zulu pin sí méjì! àwon ìlàjì ni inú ìlù nígbà tí àwon ìlàjì yókù sì wà ní ìgberíko tí wón ń sisé àgbè. Mílíònù mésàn-án ènìyàn ló ń so èdè Zulu. Èdè yìí jé òkan lára àwon èdè ìjoba mókànlá ilè South Africa. Àkoto Rómàniù ni wón fi ń ko èdè náà.  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 South Africa grows to 44.8 million, on the site southafrica.info published for the International Marketing Council of South Africa, dated 9 July 2003, retrieved 4 March 2005.