Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 20 Oṣù Kínní
Appearance
- 2009 - Barack Obama di Ààrẹ (àwòrán èdìdí) orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà; òhun ni aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́ tó bọ́ sí ipò yí.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1873 – Johannes Vilhelm Jensen, ẹlẹ́bùn Nobel ará Dẹ́nmárkì (al. 1950)
- 1931 – David Lee, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà
- 1950 – Mahamane Ousmane, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Niger
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1973 – Amilcar Cabral, olóṣẹ̀lú ará Guinea Bissau ati Cape Verde (ib. 1924)
- 1983 – Garrincha, agbábọ́ọ́lù ẹlẹ́sẹ ará Brasil (ib. 1933)
- 1988 – Khan Abdul Ghaffar Khan, alákitiyan ọmọ Pashtun (ib. 1890)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |