Guinea-Bissau

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Guinea Bissau)
Jump to navigation Jump to search
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Guinea-Bissau
Republic of Guinea-Bissau
República da Guiné-Bissau
Àsìá Emblem
MottoPọrtugí: ["Unidade, Luta, Progresso"] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  
"Unity, Struggle, Progress"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèPọrtugí: ["Esta é a Nossa Pátria Bem Amada"] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  
"This is Our Well-Beloved Motherland"
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Bissau
11°52′N 15°36′W / 11.867°N 15.6°W / 11.867; -15.6
Èdè àlòṣiṣẹ́ Portugi
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Crioulo
Orúkọ aráàlú Ará Guinea-Bissau
Ìjọba Orile-ede olominira sistemu aare die
 -  Aare José Mário Vaz
 -  Alakoso Agba Carlos Correia
Ilominira latodo Portugal 
 -  Fifilole 24 Osu Kesan, 1973 
 -  Didamo 10 Osu Kesan, 1974 
 -  Ojo Ajodun Orile-ede 24 Osu Kesan 24 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 36,125 km2 (136th)
13,948 sq mi 
 -  Omi (%) 22.4
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2010 1,647,000[2] (148th)
 -  2002 census 1,345,479 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 44.1/km2 (154th)
115.5/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $1.720 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,068[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $826 million[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $512[3] 
Gini (1993) 47 (high
HDI (2007) 0.396 (low) (173rd)
Owóníná West African CFA franc (XOF)
Àkókò ilẹ̀àmùrè GMT (UTC+0)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ otun
Àmìọ̀rọ̀ Internet .gw
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 245

Guinea-Bissau tabi Orile-ede Olominira ile Guinea-Bissau (pípè /ˈɡɪni bɪˈsaʊ/; Pọrtugí: [República da Guiné-Bissau] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pípè [ʁɛˈpublikɐ dɐ ɡiˈnɛ biˈsaw]) budo si Iwoorun Afrika. O ni bode mo Senegal ni ariwa, ati Guinea ni guusu ati ilaorun, ati mo Okun Atlantiki ni iwoorun.

Aala ile re to 37,000 square kilometres (14,000 sq mi) pelu awon olugbe ti idiye won to 1,600,000.

Guinea-Bissau je ara ileoba Gabu nigbakan, to je apa Ileobaluaye Mali; awon apa ileoba wa titi di orundun kejidinlogun, nigba ti awon miran si je apa Ileobaluaye Portugal. Nigba na lo wa di ibiamusin Portugal toruko re unje Guinea Portugi ni orundun 19th. Leyin ilominira, to je fifilole ni 1973 to si je didamo ni 1974, oruko oluilu re, Bissau, je fifikun mo oruko orile-ede lati dena iaru po mo Orile-ede Olominira ile Guinea.

14% nikan awon olugbe ni won mo ede onibise, Portugi so. Awon 44% uso Kriol, ede to da lori Portugi, awon yioku unso awon ede abinibi Afrika. Awon esin kanka ibe ni esin Islam ati awon esin ibile Afrika.

O je omo egbe Isokan Afrika, Agbajo Okowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika, Agbajo Ipejo Onimale, Isokan Latini, Agbajo awon Orile-ede Ede Portugi, La Francophonie ati South Atlantic Peace and Cooperation Zone.

Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè tenikookan re je ikan larin awon tokerejulo lagbaye.

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilominira[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iselu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon agbegbe ati apa ile Guinea-Bissau[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Guinea-Bissau je pipin si awon agbegbe 8 ([regiões] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) ati apa ibi aladawa kan ([sector autónomo] error: {{lang}}: text has italic markup (help)). Awon wonyi na tun wa je pinpin si apa metadinlogoji. Awon agbegbe ohun niyi:

* autonomous sector
Map of the regions of Guinea-Bissau

Jeografi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon ilu pataki[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cities in Guinea-Bissau
Rank City Population Region
1979 Census 2005 estimate
1 Bissau 109,214 388,028 Bissau
2 Bafatá 13,429 22,521 Bafatá
3 Gabú 7,803 14,430 Gabú
4 Bissorã N/A 12,688 Oio
5 Bolama 9,100 10,769 Bolama
6 Cacheu 7,600 10,490 Cacheu
7 Bubaque 8,400 9,941 Bolama
8 Catió 5,170 9,898 Tombali
9 Mansôa 5,390 7,821 Oio
10 Buba N/A 7,779 Quinara
11 Quebo N/A 7,072 Quinara
12 Canchungo 4,965 6,853 Cacheu
13 Farim 4,468 6,792 Oio
14 Quinhámel N/A 3,128 Biombo
15 Fulacunda N/A 1,327 Quinara

Ojuojo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Okowo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aworan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Demografiki[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Crossing the river at low tide
Religion in Guinea-Bissau,[4][5]
religion percent
Islam
  
50%
Indigenous
  
40%
Christianity
  
10%

Awon eya eniyan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ede[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Esin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilera[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Eko[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Asa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Orisun[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Joshua B. Forrest, Lineages of State Fragility. Rural Civil Society in Guinea-Bissau (Ohio University Press/James Currey Ltd., 2003).
  • Richard Andrew Lobban, Jr. and Peter Karibe Mendy, Historical Dictionary of the Republic of Guinea-Bissau, third edition (Scarecrow Press, 1997) ISBN 0-8108-3226-7 (includes extensive bibliography)

Ijapo lode[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Sisterlinks

Government
Awifun gbogbogbo
Iroyin

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Background Note: Guinea-Bissau". US Department of State. December, 2009. Retrieved 7 February 2010.  Check date values in: |date= (help)
  2. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Guinea-Bissau". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21. 
  4. CIA the World Factbook
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named EB