Jump to content

Amilcar Cabral

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Amilcar Cabral

Amílcar Lopes da Costa Cabral (Pípè ni Potogí: [ɐˈmilkaɾ ˈlɔpɨʃ kɐˈbɾal]; (1924-09-12)12 Oṣù Kẹ̀sán 1924 – (1973-01-20)20 Oṣù Kínní 1973) jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ iṣẹ́-àgbẹ̀, olùkọwé, Marksistì, agbógunti ìmúnisìn àti olóṣèlú ará Guinea-Bissau.


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]